Wọn ri foonu olukọ Fasiti Ilọrin to dawati ni Lafiagi 

Ibrahim Alagunmu, Ilorin Ọjọ Ẹti, Furaidee yii, ni wọn ri ẹrọ ibanisọrọ Ọjọgbọn Raphael Babatunde Adeniyi,…

Ọwọ yẹpẹrẹ nijọba Buhari fi mu eto aabo lorileede yii- Awọn gomina ẹgbẹ PDP tẹlẹ

Faith Adebọla Pẹlu bi orileede wa ṣe n koju ipenija eto aabo bayii, agbarijọ awọn gomina…

Nitori pe wọn ṣepolongo fun Tinubu, ẹgbẹ APC le ọmọ ẹgbẹ wọn meji danu l’Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Nitori pe wọn dara pọ mọ SWAGA, iyẹn ẹgbẹ to n ṣepolongo fun Aṣiwaju Bọla…

Ileeṣẹ ti wọn ti n ṣe ọda jona ni Kwara, ọpọ dukia lo ṣofo  

Ibrahim Alagunmu, Ilorin Ọjọruu, Wẹsidee, ọṣẹ yii, ni ina sẹ yọ nileesẹ ti wọn ti n…

Wọn tun paayan rẹpẹtẹ lasiko ija awọn ọmọ iṣọta n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan O kere tan, eeyan mẹfa la gbọ pe wọn j’Ọlọrun nipe nigboro Ibadan,…

Ọdaju ma ni Kayọde yii o, iyawo baba rẹ lo fipa ba laṣepọ l’Ayetoro-Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ọkunrin kan, Kayọde Ogundele, ẹni ọdun marundinlaaadọrin, to n ṣiṣẹ kafinta niluu Ayetoro-Ekiti, nijọba ibilẹ Ido/Ọsin, nipinlẹ Ekiti, ti…

Ija Oyetọla ati Arẹgbẹṣọla: Ẹgbẹ APC Ọṣun tun da kọmiṣanna tẹlẹ fọrọ ijọba ibilẹ atoye jijẹ duro

Florence Babaṣọla O da bii ẹni pe ọrọ ti wọn n pe lowe tẹlẹ ninu ẹgbẹ…

Adajọ ni ki wọn yẹgi fun Ọlajide titi ẹmi yoo fi bọ lara rẹ

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ile-ẹjọ giga ti ipinlẹ Ekiti, to wa l’Ado-Ekiti, ti paṣẹ pe ki wọn so ọmọ…

Tọpẹ Alabi sọrẹnda, o tọrọ aforiji lori ọrọ to sọ nipa orin ‘Oniduuro Mi’

Faith Adebọla  Boya awuyewuye to n lọ nigboro lori ọrọ abuku ti gbajugbaja onkọrin ẹmi nni,…

Awọn akẹkọọ yunifasiti lu Oluṣọla to ja wọn lole pa l’Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ọmọkunrin kan, Sunday Oluṣọla, ku iku ojiji l’Ọjọruu, ọjọ kẹrindinlogun, oṣu kẹfa yii,…

Iya atọmọ ji ọkada gbe n’Ileefẹ

Florence Babaṣọla Iyaale ile kan, Patience Ayube, ẹni ọdun mejilelaadọta, ati ọmọ rẹ, Josiah Ayube, to…