Tunde Kelani ṣafihan fiimu itan igbesi aye Ayinla Ọmọwura

Faith Adebọla Ẹsẹ ko gbero lọjọ Aiku, Sannde yii, nibi ti wọn ti ko fiimu tuntun…

Ẹ wo Kayọde to n ba ọmọ bibi inu ẹ laṣepọ n’Ikorodu

Faith Adebọla, Eko  Kayọde Adeyanju lorukọ baba ẹni ọdun marundinlaaadọta yii, ṣugbọn o ti dero ahamọ…

Awọn obi Toyin ti ọrẹkunrin rẹ ge ori rẹ l’Apomu ni: Iru iku ti wọn fi pa ọmọ wa naa ni ki wọn fi pa awọn to pa a

Florence Babaṣọla, Oṣogbo ati Idowu Akinrẹmi, Ikire Ọwọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ọṣun ti tẹ ọmọkunrin kan…

Awọn Fulani to sa kuro n’Igangan ya wọ Igbẹti, lawọn araalu ba dawo ọkọ fun wọn pe ki wọn maa lọ

Olu Theo Ọmọlohun, Oke-Ogun Ko din laaadọrin (70) awọn Fulani darandaran ti wọn sa kuro n’Igangan, nijọba ibilẹ Ila-Oorun Ibarapa, lẹyin ikọlu ti wọn ṣe sawọn…

Ọpe o, wọn ti tu agbẹ ti wọn ji gbe l’Ekiti silẹ lẹyin to san miliọnu meji naira

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Agbe kan ti awọn ajinigbe ji gbe ni Iyemero-Ekiti, nipinlẹ Ekiti, Alaaji Jimoh…

Wọn ni Emir Ilọrin fẹẹ fọba Hausa jẹ ni Jẹbba, ni Kabiyesi ba ni wahala lo n fa lẹsẹ

Ibrahim Alagunmu, Ilorin Kabiyesi ilu Jẹbba, HRM Alhaji Abdulkadir Alabi Adebara, ti ṣe ikilọ pe ki…

EFCC mu Awiṣẹ, babalawo ti wọn lo lu jibiti miliọnu igba ataabọ naira l’Abẹokuta

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ọwọ ajọ EFCC to n ri si ẹsun jibiti ti ba gbajumọ babalawo…

Bi ilu ṣe ri lo jẹ ki n maa ta iru, ṣugbọn iṣẹ naa pada pe mi daadaa-Lukman

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta “Beeyan ba yan aṣọ rira ati riran lodi nitori aisowo, o daju pe…

Blessing ta ọmọ meji ni lẹgbẹrun lọna ọọdunrun naira, o lọkọ oun to tirafu fọdun meji lo fa a

 Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Atimọle, lọdọ awọn ọlọpaa, ni Blessing  Ebuneku wa bayii nipinlẹ Ogun. Bẹẹ naa si…

L’Orile-Agege, awọn ọdọ fibinu dana sun afurasi ajinigbe pẹlu ọkọ ayọkẹlẹ ẹ

Faith Adebọla Idajọ oju-ẹsẹ lawọn ọdọ tinu n bi ṣe fun afurasi ajinigbe kan tọwọ wọn…

Ọpẹ o! Wọn ti ri Akin to pa ọrẹbinrin rẹ lẹyin to ba a sun tan niluu Apomu mu

   Florence Babaṣọla Ọwọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ọṣun ti tẹ ọmọkunrin kan ti wọn n pe…