Ọpẹ o, Korona ti lọ lara Igbakeji Gomina Kwara 

Stephen Ajagbe, Ilorin Esi ayẹwo Igbakeji Gomina Kwara to tun jẹ alaga igbimọ to n gbogun…

Ẹwọn n run nimu Kingsley, ọmọ ọdun mẹtala lo fipa ba laṣepọ ni Kwara

Stephen Ajagbe, Ilorin Fun ẹsun fifipa ba ọmọ ọdun mẹtala kan laṣepọ, ile-ẹjọ Magisreeti kan niluu…

“Ẹ ba wa dupẹ lọwọ Ọlọrun ti baaluu to ja yii ko pa wa mọnu ile”

Orin ọpẹ ati ijo ayọ lawọn ti wọn n gbe ni ojule kẹrinlelogun, Ọna Salvation, ni…

Awakọ pa ọlọkada sori afara niluu Ilọrin 

Stephen Ajagbe, Ilọrin Ọlọkada kan ti ko ti i sẹni to mọ orukọ rẹ pade iku…

Ẹni kan to ku ninu ọkọ-ofurufu to jabọ lEkoo lanaa naa ti ku o

Awọn mẹta ni wọn wa ninu ọko ofurufu agberapaa (hẹlikoputa) to jabọ saarin ile meji lagbegbe…

Ẹ fi papa iṣere Ilọrin sọri Rashidi Yẹkini- Pinnick

Stephen Ajagbe, Ilọrin Lọna ati bu ọla fun ogbontarigi agbabọọlu ilẹ wa to ti doloogbe, Rashidi…

O ṣẹlẹ, kọmiṣanna kọwe fipo silẹ ni Kwara

Stephen Ajagbe, Ilorin Lẹyin ọsẹ kan ti oludamọran pataki feto ilera, Ọjọgbọn Wale Suleiman, kọwe fipo rẹ…

Ipinlẹ Ekiti yoo bẹrẹ ayẹwo fawọn to fẹẹ darapọ mọ ikọ Amọtẹkun lọjọ Aje

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ijọba ipinlẹ Ekiti, nipasẹ igbimọ to n ṣakoso ikọ Amọtẹkun, yoo bẹrẹ ayẹwo…

Ẹwọn ọdun mẹwaa ladajọ ju Bọlanle si ni Sokoto

Oluyinka Soyemi, Ado-EkitI Idajọ ẹwọn ọdun mẹwaa gbako ni ọkunrin kan, Bọlanle Adefẹmiwa, gba nipinlẹ Sokoto…

Baaluu agberapaa ja bọ sori ile kan n’Ikẹja, eeyan meji lo ku

Ọkọ ofurufu agberapaa kan ti nijamba ni adugbo Ọpẹbi, niluu Eko. Gẹgẹ bi ẹni tiṣẹlẹ naa…

Eyi ni bawọn aṣaaju Hausa-Fulani ṣe ba Naijiria yii jẹ (14)

Awọn ọrọ ti mo n sọ wọnyi, mo fẹ ka ṣe akọsilẹ ati afọkansi wọn daradara.…