Nitori orin ‘Oniduuro Mi’, Iyabọ Ojo sọrọ buruku sawọn oṣere ẹgbẹ ẹ

Faith Adebọla  Ilu-mọ-ọn-ka oṣere tiata ilẹ wa nni, Iyabọ Ojo, ti sọko ọrọ sawọn oṣere ẹlẹgbẹ…

Nitori ki wọn ma baa sanwo ti wọn jẹ ẹ, awọn eleyii pa ọrẹ wọn, wọn ju oku ẹ si kanga

Awọn ọkunrin meji yii ti wa lọdọ awọn ọlọpaa nipinlẹ Kaduna bayii, wọn n ṣalaye lori…

Owo lolukọ Fasiti Ilọrin yii fẹẹ lọọ gba ni banki to fi dawati ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilorin Olukọ ile ẹkọ giga Fasiti ilu Ilọrin, Ọjọgbọn Raphael Babatunde Adeniyi, ẹni ọdun…

Ọmọ ọdun mẹẹẹdogun dero ẹwọn, nitori akẹkọọ ẹgbẹ ẹ to lu pa l’Abẹokuta

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Igbẹjọ waye lọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọjọ kẹrinla, oṣu kẹfa yii, lori ọmọdekunrin kan…

Akeredolu tun fẹyin Jẹgẹdẹ janlẹ nile-ẹjọ lẹẹkeji

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ile-ẹjọ ko-tẹ-mi-lọrun to fikalẹ siluu Akurẹ tun ti fontẹ lu bi ajọ eleto…

Awọn janduku mura bii fijilante, wọn bẹ sikiọriti lori, wọn dana sunle kọmiṣanna eto idajọ tẹlẹ

Eto aabo to polukurumuṣu lapa Ila-Oorun ilẹ wa, iyẹn ilẹ Ibo, tun gba ọna mi-in yọ…

Agbẹ to pa Fulani ni Kwara ni: O fi maaluu jẹko mi ni mo ṣe pa a  

Ibrahim Alagunmu, Ilorin Ọkunrin agbẹ to yinbọn pa Fulani darandaran nipinlẹ Kwara, Sẹgun Adebayọ, ti sọ…

Ogun miliọnu lawọn to ji Jimoh gbe ni Kwara n beere 

Ibrahim Alagunmu, Ilorin Awọn ajinigbe to ji Aburo Magaji Iyemọja, Jimoh Mujemu, gbe ni agbegbe Mandi…

Wọn gbe Baba Ijẹṣa wa sile-ẹjọ, ladajọ ba ni ki wọn tun da a pada satimọle

Faith Adebọla, Eko Lẹyin oṣu meji to ti wa lahaamọ awọn ọlọpaa latari ẹsun fifipa ba…

Ijọba apapọ beere agbara lati maa ṣakoso gbogbo iroyin ori ẹrọ ayelujara

Faith Adebọla  Ijọba apapọ ti sọ fun ile-igbimọ aṣofin apapọ ilẹ wa l’Abuja pe awọn fẹ…

Eeyan meji ku, ọpọ fara pa, lasiko tawọn to n ja tikẹẹti kọju ija sawọn ọlọja n’Ibadan

Awọn to ba laya nikan lo le gba agbegbe Iwo Road, niluu Ibadan kọja ni Ọjọruu,…