Faith Adebọla Titi di asiko ta a fi n ko iroyin yii jọ, ọsibitu ni baale…
Eyi lawọn oṣere ilẹ wa tiku mu lọ laarin wa lọdun yii
Florence Babaṣọla Oniruuru iṣẹlẹ a-gbọ-sọgbanu to ṣẹlẹ kaakiri orileede Naijiria ninu ọdun 2023 yii ko yọ…
Owo wọgbo: Ọmọ Naijiria yii fẹnu kọ niluu Oyinbo, ni wọn ba sọ ọ sẹwọn
Adewale Adeoye Iwaju Onidaajọ Ọgbẹni William Wood, tile-ẹjọ giga kan to wa lagbegbe Perth Sheriff, lorile-ede Scotland, ni wọn…
Ibinu buruku ti gbe Adebayọ de ọgba ẹwọn Kirikiri, ọrẹ rẹ lo gun pa
Adewale Adeoye Iwaju Onidaajọ Balogun, tile-ẹjọ Majisireeti kan to wa niluu Yaba, nipinlẹ Eko, ni wọn…
Ẹyin tẹ ẹ n ra waini, ẹ fura o: NAFDAC tun ṣawari ibi ti wọn ti n pọn ayederu waini, eeyan mẹwaa lọwọ tẹ
Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Afi ki gbogbo awọn ti wọn ba fẹẹ ra awọn ohun mimu, paapaa…
Ajalu buruku! Alaga kansu ku lasiko to n ki awọn Onigbagbọ kiri lọjọ ọdun Keresi l’Ejigbo
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Lasiko ti awọn eeyan n ṣe ajọyọ, ti wọn si n ṣe pọpọṣinṣin…
Ọwọ ọlọpaa ti tẹ Emmanuel, panẹẹli ina solar lo lọọ ji tu
Ibrahim Alagunmu Akolo ileeṣẹ ọlọpaa ẹka tipinlẹ Eko, ni afurasi adigunjale kan, Emmanuel Achogwu, ẹni ọgbọn…
Iya yii fẹẹ farugbo ara ṣẹwọn, egboogi oloro loun at’ọmọ ẹ n ta l’Ekoo
Faith Adebọla Geeti ọgba ẹwọn ti n ṣẹwọ wẹlẹwẹlẹ si mama arugbo ẹni aadọrin ọdun kan, Sẹlifat…
Baba agbalagba yii yoo pẹ lẹwọn o, ọrọ fisa ilu oyinbo lo fi n lu awọn eeyan ni jibiti l’Akurẹ
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ile-ẹjọ Majisireeti kan to fikalẹ siluu Akurẹ, ti ni ki baba agbalagba kan,…
Lawal ji mọto ọga ẹ gbe l’Ekoo, lo ba lọọ ta a fun wọn n’llọrin
Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Akolo ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Kwara ni Ọgbẹni Lawal Sulyman, ti wọn fẹsun kan…
Ọwọ ọlọpaa tẹ ikọ adigunjale ẹlẹni marun-un to n yọ awọn araalu lẹnu
Adewale Adeoye Ọdọ awọn alaṣẹ ileeṣẹ ọlọpaa agbegbe Kurmi, nijọba ibilẹ Bakori, nipinlẹ Katsina, lawọn ikọ adigunjale ẹlẹni marun-un kan ti wọn maa n…