Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Titi ta a fi pari akojọpọ iroyin yii ni awọn ọlọpaa ipinlẹ Ogun…
Ẹgbẹrun marundinlọgọta naira la maa san fun oṣiṣẹ to kere ju lọ l’Ekoo – Sanwo-Olu
Faith Adebọla, Eko Atẹwọ ayọ rẹpẹtẹ lo rọjo lọjọ Abamẹta, Satide yii, nibi ayẹyẹ ayajọ awọn…
Afẹnifẹre ṣayẹyẹ aadọrin ọdun ifilọlẹ ẹgbẹ wọn l’Akurẹ
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọgọọrọ eeyan ni wọn pejọ sinu ijọ Anglican Dafidi mimọ to wa lagbegbe…
Muhammed, ọmọ Fulani, to n da awọn eeyan lọna labule Agbagi ti bọ sọwọ ọlọpaa
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Muhammed Altine lorukọ ọkunrin pupa yii, ọkan ninu awọn Fulani to maa n…
Ṣẹgun ra ọkada lọwọ ẹni to pade lẹwọn, lo ba loun ko mọ pe ẹru ole ni
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Bo tilẹ jẹ pe ọkunrin kan, Ṣẹgun Ṣofẹla, to pe ara ẹ ni…
Lẹyin oṣu meji ti wọn ko ọpọ apo irẹsi lọ ni Bodija, awọn aṣọbode tun fọ ṣọọbu awọn onirẹsi l’Ọja Ọba
Ọlawale Ajao, Ibadan Lai tii to oṣu meji ti wọn jalẹkun ṣọọbu awọn onirẹsi lọja Bodija,…
Oṣere tiata, Lizzy Anjọrin, bimọ tuntun s’Amẹrika
Jide Alabi Idunnu ti ṣubu layọ fun ọkan ninu awọn oṣere ilẹ wa, Lizzy Anjọrin, pẹlu…
A ti sin awọn Fulani mejilelogoji ta a ko l’Okitipupa jade nipinlẹ Ondo- Adelẹyẹ
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Alakooso ẹsọ Amọtẹkun nipinlẹ Ondo, Oloye Adetunji Adelẹyẹ, ni awọn ti da awọn…
Lọọya Baba Ijẹṣa ti sọrọ o, o ni oṣere naa ati Princess ti jọ ṣe wọle-wọde ri
Sinima ere ori itage ni wahala to n lọ laarin oṣere ori itage ilẹ wa ti…
Aarọ kutu ni Ogunnaike lọọ digun ja oni POS lole, lọlọpaa ba mu un l’Abẹokuta
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Bi Rafiat Wahab, ọmọbinrin kan to ni ṣọọbu ti wọn ti n fowo…
A ṣi n ṣakojọpọ iwa itapa-sofin tawọn to n beere Orilẹ-ede Yoruba hu l’Abẹokuta- Oyeyẹmi
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Alukoro ọlọpaa nipinlẹ Ogun, DSP Abimbọla Oyeyẹmi, ti sọ pe ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ…