Ayọ abara tintin, obinrin yii bi ọmọ mẹsan-an lẹẹkan!

Faith Adebọla A ti n gbọ iya ibeji, iya ibẹta, iya mẹrin, ṣugbọn oore kẹnkẹ to…

Ẹni kan ku lojiji, ọpọ eeyan fara gbọta ‘Ikarẹ Akoko

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ẹni kan pade iku ojiji nigba tọpọ awọn eeyan mi-in tun fara gbọta…

Ayọ abara tintin, obinrin yii bi ọmọ mẹsan-an lẹẹkan!

Faith Adebọla A ti n gbọ iya ibeji, iya ibẹta, iya mẹrin, ṣugbọn oore kẹnkẹ to…

Wọn ti ni kawọn kọsitọọmu da irẹsi ti wọn ko n’Ibadan pada kiakia

Faith Adebọla, Eko  Ileegbimọ aṣofin agba ilẹ wa ti paṣẹ fawọn ileeṣẹ aṣọbode ilẹ wa, iyẹn…

Wọn tun ti ji eeyan mẹrin mi-in gbe nipinlẹ Ogun

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Eeyan mẹrin mi-in tun ti bọ sọwọ awọn ajinigbe labule Olubọ, loju ọna…

Tori Baba Ijẹṣa, awọn eeyan bu Yọmi Fabiyi, wọn lo ti kọyin sibi taye kọju si

Faith Adebọla, Eko  Bo tilẹ jẹ pe ko jọ pe eebu tawọn eeyan n fi ṣọwọ…

Ọkọ ayọkẹlẹ mewaa, oogun abẹnugọngọ lawọn ọlọpaa ka mọ awọn ọmọ ‘yahoo’  lọwọ n’Ilọrin

Stephen Ajagbe, Ilorin Afurasi ọgbọn to n lu jibiti lori ẹrọ ayelujara tawọn eeyan mọ si…

Ẹ sọ funjọba ko tete san ọgọrun-un miliọnu fawọn ajinigbe ko too pẹ ju – Sheik Gumi

Faith Adebọla  Aṣaaju ẹsin Islam nilẹ Oke-Ọya nni, Sheik Ahmad Gumi, ti sọ pe kawọn ti…

Ọkada mẹrindinlaaadọrun-un tun ha sọdọ awọn agbofinro l’Ekoo

Faith Adebọla, Eko Ọkada bii mẹrindinlaaadọrun-un nijọba gba nidii awọn to n gun wọn lọjọ Iṣẹgun,…

L’Oṣogbo, Mariam dawati, lawọn obi rẹ ba fẹsun kan pasitọ to n ṣetusilẹ fun un

Florence Babaṣọla Idile ọmọdebinrin kan, Mariam Rauf, ti wọ ṣokoto kan naa pẹlu pasitọ ijọ wọn…

Lori ẹsun ifipabanilopọ: ijọba Eko n ṣeto ẹwọn gbere fun Baba Ijẹṣa

Faith Adebọla, Eko  Bo ba jẹ ti awọn ẹsun tijọba Eko ka si Baba Ijẹṣa lẹsẹ…