Awọn agbebọn pa ẹṣọ Amọtẹkun sinu oko ni Fiditi

A-gbọ-sọgba-nu ni iku ẹṣọ Amọtekun kan, Suleiman Quadri, ẹni ọdun mẹẹẹdọgbọn tawọn agbebọn pa niluu Fiditi,…

Muhammadu to fipa ba ọmọ ọdun mẹwaa lo pọ n’Ilọrin ni iṣẹ eṣu ni

Stephen Ajagbe, Ilorin   Afurasi kan, Muhammadu Mailemu, to n gbe laduugbo Banni, lagbegbe Sango, niluu…

Ogungbangbe di Ọwaloko Iloko-Ijeṣa tuntun 

Florence Babaṣọla Gomina ipinlẹ Ọṣun, Alhaji Gboyega Oyetọla, ti kede Ọmọọba Akeem Oluṣayọ Ogungbangbe gẹgẹ bii…

Ipinlẹ Kwara ni wọn ti ri ọba Ekiti ti wọn ji gbe gba pada

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ọbadu tilu ilẹmẹṣọ-Ekiti, Ọba David Oyewumi, ti gba ominira lọwọ awọn ajinigbe to…

 Awọn agbanipa yinbọn pa Abdulfatai to n dupo Magaji niluu Ballah, ni Kwara

Stephen Ajagbe, Ilorin Alukoro ileeṣẹ ọlọpaa nipinlẹ Kwara, Ajayi Ọkasanmi, ti fidi ẹ mulẹ pe loootọ…

Awọn ọmọlẹyin Arẹgbẹṣọla ati Oyetọla ni wọn n da wahala silẹ laarin wọn-Akere

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Kọmiṣanna feto iroyin nipinlẹ Ọṣun lasiko iṣejọba Ọgbẹni Rauf Arẹgbẹṣọla, Ọnarebu Sunday Akere,…

Akẹkọọ Fasiti Ifẹ meji gbe majele jẹ, ọkan ti ku ninu wọn

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Awọn alaṣẹ Fasiti Ifẹ ti fidi rẹ mulẹ pe ọkan lara awọn akẹkọọ…

Olufọn ti Ifọn Orolu ti waja!

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Bo tilẹ jẹ pe wọn ko ti i kede fun gbogbo ilu, ALAROYE…

Sadik ati Rasak fibọn gba ẹgbẹrun lọna ọgọfa naira lọwọ onirẹsi ni Sango

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Sadik Hassan ati Kudus Rasak lẹ n wo yii, awọn mejeeji ti wa…

A maa yọ orukọ ẹgbẹ oṣelu ti ibo ablẹle wọn ba mu wahala dani danu ni- INEC

Faith Adebọla Ajọ eleto idibo ilẹ wa, Independent Electoral Commission (INEC), ti kede pe lati asiko…

Awọn alaṣẹ Fasiti Ọyẹ Ekiti fun ọkan lara awọn adari ibẹ niwee gbele-ẹ

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Awọn alaṣẹ ileewe giga Federal University Oye-Ekiti (FUOYE), ti sọ pe ki adari…