Awọn janduku dana sun ile gomina ipinlẹ Imo, wọn tun pa ẹṣọ meji

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Laaarọ ọjọ Abamẹta, Satide, ọjọ kẹrinlelogun, oṣu kẹrin yii, ni awọn janduku kan…

Ẹ kilọ fun Fayẹmi ko ma ta ilẹ wa fawọn Fulani o-PDP Ekiti 

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ẹgbẹ People’s Democratic Party (PDP) ipinlẹ Ekiti ti fẹsun kan Gomina Kayọde Fayẹmi…

Ọlọpaa ti ri Alaga ti wọn ji gbe l’Oke-Onigbin, nipinlẹ Kwara, gba pada

Stephen Ajagbe, Ilorin Ọga ọlọpaa ni Kwara, Mohammed Lawal Bagega, ti kede pe awọn doola oniṣowo…

Awọn agbebọn ji alakooso kansu l’Ekiti

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Awọn agbebọn ti ji alakooso fun eto ọgbin nijọba ibilẹ Iwọ-Oorun Ekiti, Ebenezer…

Ti mo ba tun aye wa, Yinka ni ma a fẹ – Joe Odumakin

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Iyawo Oloogbe Yinka Odumakin, Joe, ti sọ pe to ba ṣee ṣe fun…

Ara Kẹmi Afọlabi, oṣere tiata, ko ya o

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Kẹmi Afọlabi Adeṣipẹ, ọkan lara awọn oṣerebinrin nilẹ yii, ti jẹ ko di…

Awọn agbebọn ti pa mẹta ninu awọn akẹkọọ fasiti ti wọn ji gbe ni Kaduna

Mẹta ninu awọn akẹkọọ Yunifasiti Greenfield to wa niluu Kaduna, ni awọn agbebọn to ji wọn…

Ijọba ipinlẹ Ọṣun tẹwọ gba oku Yinka Odumakin ni Aṣejirẹ

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Yinka Odumakin bẹrẹ irinajo sile ikẹyin, ijọba ipinlẹ Ọṣun gba oku rẹ lọwọ…

Awọn to n bẹ ọpa epo yọnda odidi tanka fawọn Sifu Difẹnsi Ogun, wọn sa lọ patapata

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Lọjọ Ẹti, Furaidee, ọjọ kẹtalelogun, oṣu kẹrin yii, ileeṣẹ Sifu Difẹnsi ipinlẹ Ogun…

Ara kenge: APC ṣedanwo fawọn ondije sipo alaga kansu wọn ni Kaduna

Faith Adebọla Afi bii ẹni fẹẹ ṣedanwo Wayẹẹki tabi Jambu, lawọn ti wọn wọn fẹẹ dije…

Ẹ waa wo tiṣa to n fipa ba awọn akẹkọọ ọkunrin to n kọ nileewe lo pọ n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Ọwọ ọlọpaa ti tẹ olukọ ileewe aladaani kan n’Ibadan, Ọlawuyi Ebenezer, ẹni to…