Ọkọ akẹru sa f’ewurẹ, lo ba tẹ ọmọleewe mẹrin ati ọlọkada kan pa n’Ibadan                                                 

Faith Adebọla Iran buruku niran ọhun, ibanujẹ nla gbaa ni iṣẹlẹ ijamba ọkọ akẹru kan ti…

Sifu Difẹnsi sọ awọn aṣẹwo mẹẹẹdogun satimọle n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Ode ko dun fawọn oloṣo, iyẹn awọn ọdọmọbinrin ti wọn yan iṣẹ aṣẹwo…

Blessing pa iya rẹ sinu oko n’Ilẹ-Oluji, o ni ọrọ pasitọ ṣọọsi awọn loun tẹle

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọwọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ondo ti tẹ obinrin ẹni ọgbọn ọdun kan, Blessing…

Eyi ni bọwọ ṣe tẹ awọn oṣiṣẹ to ji ounjẹ ti ijọba fẹẹ pin faraalu l’Ọyọọ

Ọlawale Ajao, Ibadan Ọwọ ti tẹ awọn oṣiṣẹ ijọba ipinlẹ Ọyọ ti wọn ji ounjẹ to…

Ta o ba ṣọra, ijọba maa ta epo bẹntiroolu ni ẹẹdẹgbẹta naira kọdun yii too pari-Falana  

Faith Adebọla, Eko Agba amofin, ati ajafẹtọọ ọmọniyan nni, Oloye Fẹmi Falana, ti kegbajare pe aṣiri kan…

Awọn ajinigbe ti tu awọn mẹta ti wọn ji gbe niluu Oṣu silẹ

Florence Babaṣọla Laipẹ yii ni iroyin naa jade pe awọn ajinigbe ti tu eeyan mẹta ti…

Awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun pa eeyan mẹta l’Oṣogbo

Florence Babaṣọla   Titi di asiko ti a n koroyin yii jọ, paroparo ni agbegbe Kọlawọle,…

Awọn agbebọn ji eeyan mẹta gbe niluu Oṣu, ni wọn ba n beere miliọnu lọna aadọta naira

Florence Babaṣọla   Awọn arinrinajo mẹta la gbọ pe awọn agbebọn ji gbe lopin ọsẹ to…

Awọn ọlọpaa ti mu Ṣukura, lẹyin to pa ọmọ oṣu kan to bi lo ju oku ẹ sodo Ogun l’Abẹokuta

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta                        Ṣukurat Ọlajọkẹ lẹ n wo yii, ẹni ọdun marundinlogoji (35) to ti bimọ mẹfa…

Adajọ ju Samuel ṣẹwọn ọdun kan, ṣọọṣi lo ti lọọ jale lasiko iṣọ-oru l’Abẹokuta

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Lasiko tawọn eeyan n ṣe iṣọ-oru lọwọ ni ṣọọṣi Sẹlẹ kan, Itunu Parish,…

Nitori ọrọ to kọ sori ẹrọ ayelujara, Oyetọla ni ki alakooso Amọtẹkun fara han niwaju igbimọ oluwadii l’Ọṣun

Florence Babaṣọla Ijọba ipinlẹ Ọṣun ti paṣẹ pe ki alakooso iṣẹ awọn ikọ alaabo Amọtẹkun, Oloye…