Nitori ijinigbe, ijọba Ogun fẹẹ gba awọn ẹṣọ alaabo sawọn ileewe ijọba

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta   Pẹlu bo ṣe jẹ pe ijinigbe ti n ṣẹlẹ lawọn ileewe lawọn…

Lẹ́yìn ti wọn gba mílíọ̀nù marun-un, wọn ti tu olori ilu Imọpẹ ti wọn ji gbe silẹ

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta   Oloye TKO Ọmọtayọ, olori ilu Imọpẹ, tawọn kan jigbe lọjọ Satide to…

Awọn kan lọọ yọ geeti abawọle ileewe C&S n’Ilọrin loru

  Loruganjọ ni awọn kan lọwọ yọ geeti ileewe girama C&S, to wa ni Saabo-Oke, nìyi…

Awọn oṣiṣẹ ile-igbimọ aṣofin Ogun ti geeti pa, wọn bẹrẹ iyanṣẹlodi ailailọjọ

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Lọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọsẹ yii, ni awọn oṣiṣẹ ile-igbimọ aṣofin ipinlẹ Ogun darapọ…

Akeredolu kọ lu Sunday Igboho, o ni ko ma gbe wahala orilẹ-ede Oodua de Ondo

Jide Alabi Gomina ipinlẹ Ondo, Amofin-agba Rotimi Akeredolu, ti sọ pe ipinlẹ Ondo ko ṣetan lati…

Kaosarah, ẹni ọdun mẹrinlelogun, di kọmiṣanna ni Kwara

Stephen Ajagbe, Ilorin Akẹkọọ-jade ẹni ọdun mẹrinlelogun kan to pari ẹkọ rẹ ni Fasiti Ilọrin, Adeyi…

Eyi lawọn ileewe aladaani mẹtalelogun tijọba ti pa nipinlẹ Ọṣun

Florence Babaṣọla, Osogbo Latari bi wọn ṣe ṣi ileewe aladaani lai gba aṣẹ lọdọ ijọba, ati…

Ọwọ ọlọpaa tẹ Gbenro , iyawo rẹ lo fun lọrun pa l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Awọn ọlọpaa ipinlẹ Ondo ti fi pampẹ ofin gbe ọkunrin kan ti wọn…

Awọn ajinigbe gbe iyawo ọga-agba ileeṣẹ ijọba Ekiti tẹlẹ

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Awọn agbebọn kan ti ji iyawo olori ileeṣẹ ijọba tẹlẹ kan, Abilekọ Funmilayọ…

Justin gun ọkọ ẹ lọbẹ pa n’Ikorodu, tori aṣọ ileewe awọn ọmọ

Faith Adebọla, Eko Abilekọ ẹni ọdun mejidinlọgbọn kan, Justin Eje, ti n ṣalaye bọrọ ṣe jẹ…

Lori ọrọ hijaabu, awọn ọdọ kọ lu ṣọọṣi ‘The Apostolic’ n’llọri

  Gbogbo ferese gilaasi ileejọsin The Apostolic, to wa ni Sabo-Oke, niluu Ilọrin, ni wọn fọ…