Ko sẹni to le gba ipo mi ninu ẹgbẹ APC l’Ọṣun, Arẹgbẹ fọwọ sọya

Florence Babaṣọla Gomina ipinlẹ Ọṣun tẹlẹ, Ọgbẹni Rauf Arẹgbẹṣọla ti fọwọ mejeeji sọya pe ko si…

Ikilọ lati dẹkun dida abẹ fobinrin bẹrẹ l’Ekiti lakọtun

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Latari bi aṣa didabẹ fun obinrin ko ṣe ti i di ohun igbagbe…

Lẹyin ọdun mẹjọ to ti paayan ni Mowe, Sheu gbadajọ iku l’Abẹokuta

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Gẹgẹ bi akọsilẹ kootu ṣe wi, ọjọ kẹẹẹdogun oṣu kẹsan-an ọdun 2013 ni ọkunrin…

Nibi ti Ayuba atọrẹ ẹ ti n fibọn jale lọwọ l’Agboju lawọn ọlọpaa ti ko wọn

Faith Adebọla, Eko Ahamọ ọlọpaa ọtẹlẹmuyẹ to wa ni Panti, Yaba, nipinlẹ Eko, lawọn afurasi ọdaran…

Akeredolu yan akọwe fawọn ijọba ibilẹ mejidinlogun to wa nipinlẹ Ondo

Gomina Rotimi Akeredolu ti fọwọ si yiyan awọn akọwe fun ijọba ibilẹ mejidinlogun to wa nipinlẹ…

 Nitori obinrin, Naso gun ara ile rẹ pa loju oorun l’Akurẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọkunrin ọmọ ibo kan tawọn eeyan mọ si Naso ti n sọ tẹnu…

Awọn ọlọpaa ti ju Sẹnetọ Rochas Okorocha, gomina  ipinlẹ Imo tẹlẹ, satimọle

Faith Adebọla Gomina to ṣẹṣẹ kuro lori aleefa nipinlẹ Imo, to tun jẹ ọmọ ileegbimọ aṣofin…

Eeyan mẹrin ku ninu ijamba ọkọ l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ   Eeyan mẹrin ni wọn pade iku ojiji ninu ijamba ọkọ kan kan…

Awọn ọlọpaa ti mu awọn to pa Aborode sinu oko rẹ n’Igangan

Ọlawale Ajao, Ibadan   Lẹyin nnkan bíi oṣù meji tawọn amookunṣika pa àgbẹ aládàá nla kan…

Awọn agbebọn ji dẹrẹba ati ero mẹrin gbe loju ọna Ayetoro s’Abẹokuta

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Awakọ kan ti wọn pe orukọ ẹ ni Kamọrudeen Ọlatẹju, ti di awati…

Fulani mẹta dana sunle l’Ayetoro, wọn tun ṣa Ismaila ladaa

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Laaarọ kutu Ọjọbọ, ọjọ kejidinlogun, oṣu keji yii, ni awọn Fulani kan ko…