Mutiat Adio tun rẹwọn he lẹyin to ti ṣẹwọn lẹẹmeji

Ẹwọn ọdun mẹta ni wọn tun sọ obinrin kan, Mutiat Adio, ti ile-ẹjọ ti kọkọ sọ…

Iwọde Too-geeti: Ẹni to ba fẹẹ ja fun Naijiria gbọdọ mura lati fori la iku – Misita Macaroni

Ọkan pataki ninu awọn to foju wina ibinu awọn agbofinro lọjọ Abamẹta, Satide, ọjọ kẹtala, oṣu…

Dapọ Abiọdun ṣabẹwo si Yewa, o ṣeleri iranwọ fawọn tijamba kan

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Lọjọ Aje, Mọnde, ọsẹ yii, ti i ṣe ọjọ kẹẹẹdogun, oṣu keji, Gomina ipinlẹ…

Gbenga Daniel darapọ mọ ẹgbẹ APC

Gomina ipinlẹ Ogun tẹlẹ, Ọtunba Gbenga Daniẹl, naa ti darapọ mọ ẹgbẹ oṣelu APC bayii. Ninu…

Ijọba bẹrẹ iwadii lori ọkọ BRT to gbina lọna Ikorodu

Faith Adebọla, Eko       Ere asadigbolura-ẹni ati akọlukọgba gidi lo waye lọsan-an ọjọ Aje,…

Okonjo-Iweala di obinrin akọkọ nipo ọga agba Ajọ Olokoowo Agbaye (WTO)

Faith Adebọla       Inu ayọ ati idunnu gidi ni minisita feto iṣuna nilẹ wa…

Nitori ẹsun agbere, Ọlatunji gun iyawo ẹ pa l’Owode-Ẹgba

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹ́òkúta   Awọn atẹjiṣẹ to jọ mọ ọrọ ifẹ ti baale ile kan, Ọgbẹni…

Awọn ara ilu Oro ṣekilọ: Ki Fulani ti ko ba kuro niluu wa laarin ọjọ meje fara mọ ohun ti oju rẹ ba ri

Faith Adebọla  Awọn eeyan agbegbe Oro, nijọba ibilẹ Irẹpọdun, nipinlẹ Kwara, ti kede pe gbedeke ọjọ…

Wamuwamu lawọn ọlọpaa duro sawọn ibi kan l’Ekoo, awọn to fẹẹ ṣewọde ni wọn n ṣọ

Jide Alabi     Lati le pinwọ ikojọpọ tabi ṣiṣe iwọde lati fẹhonu han ni Too-geeti,…

Omiṣore darapọ mọ ẹgbẹ APC l’Ọṣun

Florence Babaṣọla Igbakeji gomina ipinlẹ Ọṣun nigba kan, to tun ti figba kan jẹ aṣofin to…

Awọn ẹsọ amọtẹkun gbẹsẹ le maaluu igba (200) to ba oko oloko jẹ n’Irẹsẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ   Awọn maaluu to to bii igba (200) lawọn ẹsọ amọtẹkun ẹka tipinlẹ…