Ṣebi ẹyin naa n gbọ isọkusọ lẹnu ọkunrin-kukuru-biliisi

O ṣoju mi koro (Apa Kin-in-ni)   Bo ba jẹ gbogbo awọn gomina lo ri bii…

Ẹṣẹ ti emi Taye ba ṣẹ, Kẹhinde mi lo maa n jiya rẹ nigba ta a wa ni kekere- Ibeji Ọbasa

N ba b’ejirẹ n ba jo, ai b’ejirẹ dun mi, ẹdunjọbi ọba ọmọ. Nnkan iwuri lo…

Wọn ṣeku pa ‘Tiroo’ n’Isalẹ Eko, wọn lolori ẹgbẹ okunkun ni

Faith Adebọla, Eko  Tiroo lorukọ inagijẹ ẹ, ki i ṣe tiroo tawọn obinrin n le soju…

Owo epo bẹntiroolu yoo tun lọ soke lẹẹkan si i o

  Ijọba apapọ ti sọ pe iye tawọn araalu n ra epo bẹntiroolu yoo tun lọ…

Ọwọ ọlọpaa ba awọn janduku mejidinlọgọta nisalẹ Eko, obinrin marun-un wa ninu wọn

Faith Adebọla, Eko Ahamọ awọn ọlọpaa ọtẹlẹmuyẹ to wa ni Panti, Yaba, nipinlẹ Eko, lawọn afurasi…

Ọṣinbajo, Dapọ Abiọdun, Ọṣọba tun iforukọsilẹ wọn ṣe lẹgbẹ APC Ogun

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Igbakeji Aarẹ orilẹ-ede yii, Ọjọgbọn Yẹmi Oṣinbajo, Gomina Dapọ Abiọdun ati Oloye Oluṣẹgun Ọṣoba…

Ami-ẹyẹ ko ti i tọ si mi bayii, mi o ti i gbija Yoruba debi aṣeyọri – Sunday Igboho

Ọlawale Ajao, Ibadan Nitori ipa takunakun to n ko lati gba gbogbo ilẹ Yorùbá silẹ lọwọ…

Awọn Fulani darandaran tun ti ji eeyan meje gbe loju ọna Ileṣa si Akurẹ

Florence Babaṣọla Iroyin to n tẹ wa lọwọ ti jẹ ko di mimọ pe awọn Fulani…

Lasiko ti Atẹrẹ n gbe ọmọ rẹ to n saisan lọ sọsibitu ni wọn ji i gbe n’Ilọrin

Stephen Ajagbe, Ilorin Awọn ajinigbe ti wọn to mẹfa to ji baale ile ẹni ọdun mẹrindinlaaadọta…

Nitori owo, Kamilu atọrẹ rẹ fẹẹ pa iya arugbo l’Oṣogbo

Florence Babaṣọla. Oṣogbo Awọn ọdọkunrin meji, Ọlagunju Kamilu ati Adenle Mujeem, ni wọn fara han niwaju…

Fidio: Itan Igbesi Aye Obafẹmi Awolọwọ Ori Kẹta (Apa Kin-in-ni)

ki o le je ẹkọ fun ọmọ Yoruba gbogbo. Ọdun 2019 ni a ti tẹ iwe…