Ọwọ sifu difẹnsi tẹ awọn afurasi ajinigbe marun-un l’Ọwọ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ninu igbo ọba kan lagbegbe Eti-Ọsẹ, nijọba ibilẹ Ọwọ, lọwọ awọn oṣiṣẹ ajọ…

O ga o! Eyi lohun tawọn ajafẹtọọ ṣe fun’yawo Mohbad

Monisọla Saka Wọn n pe ọrọ iku ọkunrin olorin taka-sufee ilẹ wa to ku loṣu Kẹsan-an,…

Ẹfun abeedi! Ọmọ ti obinrin yii gba tọju gun un lọbẹ pa l’Akurẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ileeṣẹ ipinlẹ Ondo ti bẹrẹ iwadii lori iku abilekọ kan, Florence Adelayi, ẹni…

Ọkẹ aimọye dukia jona deeru ninu iṣẹlẹ ijamba ina n’llọrin

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Titi di asiko ti a n ko iroyin yii jọ, inu adanu nla…

Ọkunrin yii ji ara ẹ gbe pamọ, eyi nidi to loun fi ṣe bẹẹ

Monisọla Saka Ọwọ awọn agbofinro Abuja ti tẹ ọkunrin ẹni ọdun mejidinlọgbọn (28) kan, Pascal Akuh,…

Ọrọ di ilu gangan n’Ibadan: Wọn n sunkun nile Ọba Balogun, wọn n yọ nile Ọba Ọlakulẹhin

Ọlawale Ajao, Ibadan Nibi tẹlẹkun ti n sunkun lalayọ ti n yọ, bi awọn leekan leekan…

Ilẹ mọ ba eleyii, ayederu owo Naira lo fẹẹ na fun oni POS

Adewale Adeoye Ọdọ awọn ọlọpaa ipinlẹ Eko ni Omidan Linda Ihebinike wa bayii to ti n gbatẹgun. Eyi ko sẹyin…

Iyawo fẹẹ pa ọkọ rẹ nitori ko ma baa san gbese to jẹ ẹ

Adewale Adeoye Ileeṣẹ ọlọpaa agbegbe Rafin-Guza, nipinlẹ Kaduna, ti lawọn maa too bẹrẹ  iwadii nipa ẹsun ti wọn fi kan iyaale…

O ma ṣe o, obinrin yii ṣubu lule lasiko to n kọrin ẹmi ni ṣọọṣi, lo ba ku

Adewale Adeoye Ṣe lọrọ ọhun di bo o lọ yago fun mi ninu ijọ Ọlọrun kan ti wọn n…

Adanu nla ni iku Ọba Ọlalekan Balogun jẹ fun iran wa – Yoruba Obas Forum

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Agbarijọpọ awọn lọbalọba nilẹ Yoruba, labẹ Yoruba Obas Forum (YOF), ti ranṣẹ ibanikẹdun…

Kabiesi pe ipade igbimọ Olubadan lọjọ ti wọn jade laye- Ẹkẹrin Olubadan  

 Ọlawale Ajao, Ibadan Ẹni to ko gbogbo eeyan mọra l’Ọba Lekan Balogun. Ki i ṣe ọba…