Ẹmi ọkunrin yii daṣẹ silẹ lojiji, lo ba ku sinu moto to n wa lọ l’Ekoo

Aderounmu Kazeem Lọjọ Ẹti, Furaidee, to lọ yii ni wọn ba oku ọkùnrin kan ninu mọto…

 Nitori awọn Fulani, Akeredolu ni ki wọn gba awọn oṣiṣẹ tuntun sinu ẹsọ Amotẹkun

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Gomina Rotimi Akeredolu ti fọwọ si gbigba ọgọọrọ awọn oṣiṣẹ sinu ẹsọ Amotẹkun,…

Awọn ọdọ ilu dana sun Gaa Seriki awọn Fulani n’Igangan

 Faith Adebọla Gbajumọ ajijagbara ọmọ Yoruba nni, Sunday Adeyẹmọ, tawọn eeyan mọ si Sunday Igboho, tabi…

Awọn sọja mu mẹrin balẹ ninu awọn ajinigbe to da awọn arinrin-ajo lọna l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọrọ bẹyin yọ fawọn ikọ ajinigbe kan lọjọ Ẹti, Furaidee, ọsẹ yii, pẹlu…

O ṣẹlẹ, wọn lẹni to fẹẹ jẹrii ta ko Fayoṣe nile-ẹjọ ti ko Korona

Faith Adebọla, Eko Ẹjọ ti gomina ipinlẹ Ekiti tẹlẹ, Ọgbẹni Peter Ayọdele Fayoṣe, n jẹ lọwọ…

Ẹ wo Tunde, awakọ to fipa ba obinrin lo pọ ni Mowe, to tun gbowo nla lọwọ ẹ

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹ́òkúta Tunde Bello lọkunrin ti ẹ n wo yii n jẹ, ẹni ọdun mejilelọgbọn…

O ma ṣe o, ọkan ninu awọn oṣere Fuji jade laye  

Aderounmu Kazeem Agbọ-sọgba-nu ni iku ọkan ninu awọn oṣere Fuji nilẹ wa, Alaaji Tajudeen Iṣọla, ti…

EFCC ya wọ Oṣogbo, wọn ko afurasi mọkanla pẹlu ọkọ ayọkẹlẹ mejila

Florence Babaṣọla Oju ọjọ ko dara lọjọ Ẹti, Furaidee, opin ọsẹ yii, fun awọn afurasi onijibiti…

Ẹnu-ọna baaluu lọwọ ti ba awọn ọmọge meji yii, ayederu iwe irinna ni wọn feẹ lo

Faith Adebọla, Eko     Ahamọ awọn agbofinro to n ri si iwọle ati ijade kuro…

 Awọn Fulani darandaran lọọ ka awọn agbẹ mọ inu oko wọn l’Akurẹ, wọn si ṣa wọn bii ẹran

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọrọ awọn Fulani darandaran to n ṣoro bii agbọn nipinlẹ Ondo tun ba…

Ọwọ ẹṣọ Amọtẹkun tẹ awọn ajinigbe mẹrin l’Ekiti

Jide Alabi  Lọjọ Ẹti, Furaidee, opin ọsẹ yii, ni ọwọ ẹsọ Amọtẹkun tẹ awọn ajinigbe mẹrin…