Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Wahala to n ṣẹlẹ nile igbimọ aṣofin ipinlẹ Ondo gbọna mi-in yọ laaarọ…
Ileeṣẹ aṣọbode mu kẹkẹ maruwa atọkọ bọọsi awọn fayawọ
Stephen Ajagbe, Ilọrin Ileeṣẹ aṣọbode ilẹ yii, ẹka tipinlẹ Kwara, ti ṣafihan awọn kẹkẹ maruwa kan pẹlu…
Awọn to ni ibaṣepọ pẹlu Logun ti wa ni iyasọtọ – Ijọba Kwara
Stephen Ajagbe, Ilọrin Ijọba ipinlẹ Kwara ti kede pe gbogbo awọn to ni ibaṣepọ pẹlu Aminu…
Koronafairairọọsi pa Aminu Logun, olori oṣiṣẹ lọfiisi gomina Kwara
Stephen Ajagbe, Ilorin Ijọba ipinlẹ Kwara ti fidi ẹ mulẹ pe arun Koronafairọọsi lo pa Aminu…
O maa ṣe o! Olori oṣiṣẹ lọfiisi gomina Kwara ti ku o
Stephen Ajagbe, Ilorin Iroyin kan to tẹ wa lọwọ sọ pe Alhaji Aminu Logun ti i…
Lẹyin ti Wasiu tẹwọn de lo tun lọọ ja ọkada gba n’Ipokia
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Bi iṣẹ kan ba wa ti ọmọkunrin kan, Wasiu Raji, fẹran lati maa…
Eyi ni bawọn aṣofin Ondo ṣe fẹẹ yọ igbakeji gomina
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Lonii, ọjọ Iṣẹgun,lawọn ọmọ ile igbimọ aṣofin bẹrẹ igbesẹ yiyọ Ọnarebu Agboọla Ajayi…
Baba mi lo nifẹẹ si iṣẹ ṣọja, nitori tiwọn ni mo ṣe wa nileewe naa bayii – Lọọya Kunle
Ọdọmọde ni, nitori ọjọ ori rẹ ko ju mẹẹẹdọgbọn(25), lọ. Ṣugbọn iṣẹ adẹrin-in-poṣonu to n ṣe…
Awọn aṣofin Eko buwọ lu atunṣe eto iṣuna
Faith Adebọla, Eko Ile igbimọ aṣofin ipinlẹ Eko ti ṣagbeyẹwo aba eto iṣuna ipinlẹ naa lakọtun,…
Kayeefi nla! Niluu Ifọn, ara san pa maaluu meje
Fun igba akọkọ niluu Ifọn Ọṣun, maaluu meje ni ara nla to san lasiko ojo nla…
Ondo: Oluwatuyi di akọwe ijọba, bẹẹ ni Ọtẹtubi yoo di kọmiṣanna laipẹ
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Gomina Rotimi Akeredolu tipinlẹ Ondo ti yan akọwe ijọba tuntun, Temitayọ Oluwatuyi. Eyi…