Eyi ni bi onilu Ayinla Ọmọwura, Adewọle Alao, ṣe ku gan-an

Jide Alabi ati Adefunkẹ Adebiyi Laṣaalẹ ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọjọ kọkandinlọgbọn, oṣu kejila, ọdun 2020, ni…

Aṣiri nla! Idi ti Pasitọ Bakare fi d’ọrẹ Tinubu lojiji ree o

Ọjọ naa lo da bii ana yii. Ọjọ Sannde kan bayii, ọjọ kejilelogun, oṣu kẹsan-an, ọdun…

Tunde, awọn wo ni Agba Ṣakabula?

N ko fẹẹ sọrọ si ọrọ yii rara, ṣugbọn ọrọ naa jo mi lara, nitori ki…

 Adewọle Alao, onilu Ayinla Ọmọwura, ti ku o

Jide Alabi Lẹyin bii ọjọ meloo kan ti awọn ẹgbẹ Ayinla Ọmọwura lori ẹrọ ayelujara ṣe…

Ko sidii fun Naijiria lati toṣi- Ọbasanjọ 

Faith Adebọla “Ọlọrun kọ lo jẹbi ohun to n ṣẹlẹ si wa lorileede yii, awa funra…

Nitori Korona: Ijọ Ridiimu fagi le isin aisun-ọdun tuntun

Jide Alabi Ijọ Ridiimu ti sọ pe ko ni i si anfaani lati kora jọ papọ…

 Ijọba Ondo kilọ fun ẹgbẹ CAN: Ẹni to ba ṣe isọ-oru wọnu ọdun tuntun n fẹwọn ṣere.

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ijọba ipinlẹ Ondo ti fa ibinu nla yọ latari ọrọ ti Alaga ẹgbẹ…

 Eyi ni bi wọn ṣe pa awọn obinrin meji laarin ọjọ kan ṣoṣo l’Akurẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ki i ṣe ibẹru kekere niṣẹlẹ iku awọn obinrin meji kan ti wọn…

Lasiko ti Lekan fẹẹ fọle onile lo bọ sọwọ awọn agbofinro n’Ibẹju-Lẹkki

Faith Adebọla, Eko Ori lo ko awọn olugbe ile kan lagbegbe Ibẹju-Lẹkki, nipinlẹ Eko, yọ, diẹ…

Ọwọ ọlọpaa tẹ mẹrinla ninu awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun to n yọ wọn lẹnu n’Ikorodu

Faith Adebọla, Eko Mẹrinla lara awọn afurasi ọmọ ẹgbẹ okunkun ‘Aiye’ to n da wahala silẹ…

Awọn tọọgi kọju ija sira wọn l’Ejigbo, ni wọn ba yinbọn pa Abeeb

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọmọdekunrin kan, Abeeb Abifarin, lo ti jẹ Ọlọrun nipe laago mẹjọ ku diẹ…