Ọga agba ileeṣẹ ijọba ku sọfiisi rẹ n’Ilọrin

Stephen Ajagbe, Ilorin   Titi di asiko yii, ko ti i sẹni to mọ iru iku to…

Ẹgbẹ oṣiṣẹ kilọ fun ijọba, wọn ni wọn ko gbọdọ le awọn oṣiṣẹ ile aṣofin

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Agbarijọpọ ẹgbẹ oṣiṣẹ nipinlẹ Ekiti ti kede pe awọn ko ni i gba…

Lẹyin tawọn Fulani fi maaluu jẹ oko Rilwan tan ni wọn tun ṣa a pa l’Odo-Ọtin

Florence Babaṣọla Inu aibalẹ aya lawọn eeyan ilu Ijabẹ, nijọba ibilẹ Odo-Ọtin, nipinlẹ Ọṣun, wa bayii, pẹlu bi awọn Fulani bororo…

Ọwọ EFCC tẹ awọn ọmọ ‘Yahoo’ mẹwaa l’Alagbado

Faith Adebọla, Eko   Awọn mẹwaa ni wọn ti wa lakata ajọ to n gbogun ti…

Peter fun ọmọ to bi ninu ara rẹ lo loyun l’Ondo, lo ba lo ṣeeṣi ni

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ   Ile-ẹjọ Majisireeti to wa niluu Ọrẹ, nijọba ibilẹ Odigbo, ti ni ki wọn ṣi lọọ fi…

Eeyan mẹẹẹdọgbọn ku ninu ija awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun l’Ogun

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Pẹlu bi ija agba ṣe n waye lemọlemọ laarin awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun oriṣiiriṣii kaakiri…

Nibi tawọn eleyii ti fẹẹ gbe egboogi oloro kọja papakọ ofurufu n’Ikẹja lọwọ ti tẹ wọn

Faith Adebọla, Eko Awọn gende mẹta kan to fẹẹ gbe egboogi olori kọja papakọ ofurufun Muritala…

Awọn eeyan Ipetu Ijẹṣa ni ki gomina Ọsun le Ọwa Obokun kuro nipo, nitori to gba kabiyesi wọn leti

Aderounmu Kazeem Ko si ọmọ ilu Ipetu-Ijẹṣa nipinlẹ Ọṣun to gbọ nípa wahala to sẹlẹ láàrin…

Ẹ fura o! Wọn fẹẹ f’ọrọ ẹsin da wahala silẹ nilẹ Yoruba – DSS pariwo

Aderounmu Kazeem Ọkan lara ileeṣẹ agbofinro orilẹ ede yii, DSS, ti ke gbajare pe ki awọn…

L’Oṣogbo, ọwọ tẹ Iya Alagbo to ta ọmọ ọlọmọ lẹgbẹrun lọna aadọjọ naira

Florence Babaṣọla Ọwọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ọṣun ti tẹ obinrin alagbo kan, Ganiyat Ọladapọ, lori ẹsun…

Gift gun Gbenga lọbẹ pa n’Ibadan, wọn ni bo se pa ọkọ ẹ naa niyẹn

Ọlawale Ajao, Ibadan Bi ọkunrin ẹni ọdun mejidinlogoji (38) kan, Babafẹmi Gbenga, ba ri wolii kan…