Eyi niṣẹ ti Ẹniọla Ajao ran si Bobrisky lọgba ẹwọn

 Monisọla Saka Oṣerebinrin ilẹ wa nni, Ẹniọla Ajao, to ni sinnimọ ‘Ajakaju’, ti Idris Ọlarewaju Okunẹyẹ,…

Awọn agbebọn tun ṣọṣẹ ni Plateau, eeyan mẹtadinlogun ni wọn pa kilẹ too mọ

Faith Adebọla O kere tan, oku eeyan mẹtadinlogun lawọn agbofinro atawọn ọlọdẹ ti ri ṣa jọ…

Iwọ naa le kopa ninu eto ‘Arlington Appreciation Day’ ti yoo waye ni orileede Amẹrika

Ọrẹoluwa Adedeji Anfaani nla ti wa fun awọn ọmọ orileede yii lati darapọ mo ileeṣẹ kan…

Micheal ji ẹrọ amuletutu mẹsan-an ninu ile ti wọn ni ko maa ṣọ l’Oṣogbo

 Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ẹni a gboju okun le ti ko jọ ẹni agba ni ọrọ ọmọkunrin…

Eedi ree o: Ọlọpaa yinbọn pa iyawo rẹ at’ọmọ ọdun kan to n tọ lọwọ, lo ba tun para ẹ

Adewale Adeoye Titi di asiko ta a n koroyin yii jọ, kayeefi lọrọ ọkunrin ọlọpaa kan, Oloogbe Thembelani Lihlume, to yinbọn pa…

Awọn alaṣẹ ọgba ẹwọn ti sọrọ o: Eyi lohun ti a maa ṣe fun Bobrisky lọgba ẹwọn

Adewale Adeoye Ni bayii, awọn alaṣẹ ọgba ẹwọn orileede yii, ‘The Nigerian Correctional Services’ ẹka tipinlẹ Eko ti sọ pe inu ọgba ẹwọn awọn ọkunrin lawọn…

Baba Akintoye ati Sunday Igboho ti sọrọ: Awa o mọ nnkan kan nipa awọn to fẹẹ gbajọba n’Ibadan o

Bo tilẹ jẹ pe ariwo pe ọmọ ẹgbẹ ajijagbara fun ominira Yoruba ti wọn n pe…

Ọwọ tẹ oṣiṣẹ ileeṣẹ amunawa atawọn marun-un mi-in ti wọn ji ẹrọ tiransfọma gbe l’Abuja

Adewale Adeoye Oṣiṣẹ ileeṣẹ amunawa kan atawọn ọrẹ rẹ marun-un lọwọ ọlọpaa agbegbe Mapape, niluu Abuja, ti i ṣe olu ilẹ wa ti tẹ l’Ọjọbọ, Tọsidee, ọjọ kọkanla, oṣu Kẹrin, ọdun 2024 yii. Ẹsun tawọn agbofinro ọhun fi kan…

O ma ṣe o, kọntena re bọ sori ọkọ ayọkẹlẹ l’Alapẹrẹ, obinrin kan ku loju-ẹsẹ

Faith Adebọla Ogun a-jade-i-wọle ti ja obinrin kan tẹnikan ko ti i mọ orukọ rẹ bayii,…

Nnkan de! Awọn agbegbọn ya wọ sẹkiteriati ijọba ipinlẹ Ọyọ, wọn fẹẹ gbajọba lọwọ Makinde

Ọlawale Ajao, Ibadan Boya ni ọkan Gomina ipinlẹ Ọyọ, Ẹnjinnia Ṣeyi Makinde, yoo ti i balẹ…

Eyi lawọn ohun to ṣẹlẹ ni kootu lasiko igbẹjọ Emefiele ati EFCC

Faith Adebọla Ko sẹni to de ayika ile-ẹjọ giga akanṣe ilu Eko, iyẹn Special Offences Court, to…