Iku Oloye Bọla Ige ti wọn ni mo lọwọ ninu rẹ, eyi ni b’ọrọ ṣe jẹ-Sunday Igboho

Adewale Adeoye ‘’Irọ buruku ni wọn pa mọ mi. Emi o lọwọ ninu iku Oloye Bọla…

Eyi le o! Obinrin yii ji ara ẹ gbe, o loun fẹẹ fi gbowo lọwọ ẹgbọn oun ni

Ọwọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Akwa Ibom, ti tẹ obinrin kan, Imaobong Sampson, to parọ pe wọn…

Nnkan de! Wọn ba oku sifu difẹnsi ninu kanga l’Ọṣun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Oṣiṣẹ ajọ sifu difẹnsi kan ti wọn ti n fi ọpọlọpọ ọjọ wa…

Kayeefi! Lasiko ti dẹrẹba yii n wakọ lọ ku lojiji ni Fasiti Ilọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Inu ibanujẹ ati ọfọ ni mọlẹbi Lukman to jẹ dẹrẹba, to n fọkọ…

Peter yii ma daju o, laarin ọjọ meje ti wọn gba a siṣẹ lo pa ọga ẹ l’Ekoo

Inu ibanujẹ lawọn mọlẹbi ati aladuugbo mama kan ti ko ti i sẹni to mọ orukọ…

Ko saaye fun gomina lati maa fi ẹni to ba wu u jẹ alaga kansu mọ ni ipinlẹ Ọyọ -Alaga OYSIEC

Ọlawale Ajao, Ibadan Ko ni i ṣee ṣe fawọn gomina ipinlẹ Ọyó lati maa yan ẹni…

Ikunlẹ abiyamọ o! Lẹyin ti wọn gun obinrin yii lọbẹ pa tan ni wọn yọ ọkan ẹ lọ

Monisọla Saka Amookunṣeka ẹda kan ti da ẹmi Arabinrin Tina Ileogben legbodo, lẹyin to gun un…

O ṣẹlẹ, ile-ẹjọ ni Baruwa ni ojulowo aarẹ ẹgbẹ onimoto  l’Abuja

Adewale Adeoye Ẹsẹ ko gbero ni kootu ajọ oṣiṣẹ, ‘National Industrial Court’, to wa niluu Abuja, ti i ṣe olu ilẹ wa, lọjọ Aje, Mọnde, ọjọ kọkanla, oṣu Kẹta, ọdun 2024 yii, lasiko ti…

Abiru ki leleyii, baba pa ọmọ ẹ lati fi ṣoogun owo

Adewale Adeoye Ọgbẹni Steady Munda ti n kawọ pọnyin rojọ lagọọ ọlọpaa kan to wa ni agbegbe Chemowa, lorileede…

L’Ọtun-Ekiti, Ọlalẹyẹ fibinu gun ẹni to n la wọn lasiko to n ja pa

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ile-ẹjọ Majisreeti kan to wa l’Ado-Ekiti, ti paṣẹ pe ki okunrin ẹni ọdun…

O ṣẹlẹ, ọmọọdun mẹtadinlogun gbe majele jẹ nitori owo ọga rẹ to ṣe baṣubaṣu

Adewale Adeoye Ileewosan kan to wa niluu Ẹpẹ, nipinlẹ Eko, ni wọn gbe oku gende kan, Oloogbe Ojibe Chibueze, ẹni ọdun mẹtadinlogun, to gbẹmi…