Awọn panapana ti ri oku ọkan lara awọn ero ọkọ to ko si odo n’Ilorin 

Stephen Ajagbe, Ilọrin Awọn oṣiṣẹ panpana ti ri oku Okechukwu Orwabo, ọkan lara awọn eeyan mẹta…

Lori gbọngan aṣa tawọn aṣofin fẹẹ fi sọri Fayẹmi, APC ati PDP sọko ọrọ sira wọn

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti O jọ pe ija ko ti i pari rara lori bi ẹgbẹ oṣelu…

Joshua ati Fury ti ṣetan lati ja nigba meji – Eddie Hearn

Oluyinka Soyemi Gbajugbaja eleto ẹṣẹ kikan, Eddie Hearn, ti kede pe Anthony Joshua ati Tyson Fury…

Miliọnu mẹwaa Yuro ni Partizan fẹẹ ta Umar Sadiq

Oluyinka Soyemi Ẹgbẹ agbabọọlu Partizan Belgade, ilẹ Serbia, ti sọ pe miliọnu mẹwa Yuro lawọn fẹẹ…

Ibo 1979 ku si dẹdẹ, n lawọn adigunjale ba ko girigiri ba awọn oloṣelu atijọba Ọbasanjọ (3)

Igba kan ti wa nilẹ yii to jẹ iṣẹ ọlọpaa a maa wuuyan i ṣe, nitori…

Lọjọ ayajọ ijọba tiwa-n-tiwa, ẹlẹwọn mejidinlọgbọn gba idariji nipinlẹ Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Lati ṣami ayajọ ijọba awa-ara-wa, Gomina Rotimi Akeredolu ti kede idariji fun mejidinlọgbọn…

Kẹhinde fipa ba abirun lo pọ l’Ọta, Musa naa tun fipa ba ọmọ ọdun mẹjọ lo pọ n’Ijẹbu-Ode

 Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Fun pe o fi tipatipa ba ọmọbinrin kan ti ara rẹ ko da…

Lẹyin ọdun marun-un lọgba ẹwọn, adajọ ni Gideon ko jẹbi ẹsun idigunjale

Florence Babasola, Osogbo Adajọ ile-ẹjọ giga kan niluu Oṣogbo, Onidaajọ Kudirat Akano ti sọ pe ki…

Ẹẹmeji ọtọọtọ lọkọ mi ti lu mi toyun-toyun, mi o fẹ ẹ mọ – Adenikẹ

Ọlawale Ajao, Ibadan “Ọkọ mi ko mọ ju ounjẹ lọ, ọna ti mo gba rowo se…

Awọn onikorona mẹrin sa lọ nibi ti wọn ti n gba itọju n’Igbẹti 

Ọlawale Ajao, Ibadan Mẹrin ninu awọn to lugbadi ajakalẹ arun Korona ti sa kuro nibi ti…

Oju Ole Re – E wo Arakunrin Olawale Olamiposi ti o n ja awon eniyan ni jibiti

Mo nkọwe lati ṣe ẹdun ọkan si Ọgbẹni Olagoke Olawale ati Iyaafin Olagoke Pejulola Bagbenro iyawo…