Ta lo n purọ: Owo dija silẹ laarin Gomina Makinde ati ileewosan UCH

Ọlawale Ajao, Ibadan Gbogbo aye lo n fi ijọba ipinlẹ Ọyọ atawọn alaṣẹ UCH, iyẹn ileewosan…

Kayeefi nla leleyii o! Baba fun ọmọ bibi inu ẹ ẹ loyun n’Ikorodu

Chibuike naa tun fipa bọmọ ọdun mẹrinla lo pọ ni Bariga Bẹẹ ni Chinedu ṣe kinni…

Ibo 1979 ku si dẹdẹ, n lawọn adigunjale ba ko girigiri ba awọn oloṣelu atijọba Ọbasanjọ (Ipari)

Ariwo, ‘yaa-fun-un yaa-fun-un’ motọ ọlọpaa lawọn eeyan to wa nile-ẹjọ giga n’Ikẹja kọkọ gbọ. Bi wọn…

O Soju Mi Koro

Alagbara lanaa da: Oshiomhole to fẹẹ gbẹsan Nigba ti Ọlọrun ba fun ni lagbara, ko si…

Eyi ni bi aarẹ ẹgbẹ Rotaract Club ilu Iwo ṣe ku nibi to ti n gba bọọlu

Florence Babaṣọla, Osogbo Bii ala lọrọ naa ṣi n jẹ loju gbogbo awọn eeyan ilu Iwo,…

Wọn ṣi n wa awọn arinrinajo mẹjọ ti wọn ji gbe ni Akoko

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ  Titi di ba a ṣe n sọ yii lawọn agbofinro atawọn ẹṣọ alaabo lẹlẹka-jẹka ṣi…

Okpara n lọọ ri Awolọwọ lẹwọn ni Calabar, o fẹẹ lọọ fẹjọ Akintọla ati awọn ọrẹ rẹ sun nibẹ ni

Ni Ọjọbọ, Alamisi, ọjọ kọkandinlogun, oṣu kọkanla, 1964, wọn ju Mark Ogbod sẹwọn ọdun kan niluu…

Safu ni Iya Dele at’Anti Sikira fẹẹ gbooru ara ninu ojo ni

Ọjọ keji ni mo too le ṣalaye ohun to ṣẹlẹ nile fun Safu.  Nigba ta a de…

Nwakali gba bọọlu fun kilọọbu lẹyin ọdun kan

Oluyinka Soyemi Lẹyin ọdun kan ati oṣu mẹta ti balogun ikọ agbabọọlu Golden Eaglets ilẹ Naijiria…

Ibo 1979 ku si dẹdẹ, n lawọn adigunjale ba ko girigiri ba awọn oloṣelu atijọba Ọbasanjọ (4)

Iroyin ti gbogbo ọmọ Naijiria ti n reti ni. Loootọ wọn ti gbọ oriṣiiriṣii iroyin lori…

Ajọ OYTMA gbẹsẹ le mọto ijọba ipinlẹ Ọyọ, wọn lo da gosiloo silẹ

Ọlawale Ajao, Ibadan “Bi gbogbo aye ba n ṣe bayii, a dun”. Eyi lọrọ ti ọpọ…