Risikatu, obinrin to ni ẹyinju to yatọ ati ọkọ rẹ so yigi n’Ilọrin

Sẹnkẹ ni inu gbogbo awọn to wa nibi adura igbeyawo ti wọn ṣe fun ọmọbinrin ti oju rẹ yatọ, to tun bi awọn ọmọ ti oju wọn yatọ niluu Ilọrin, Risikat Abdul Azeez ati ọkọ rẹ, Wasiu. Satide opin ọsẹ yii ni awọn aafaa so yigi fun tọkọ-tiyawo naa niluu Ilọrin.

Leave a Reply