Saare ti wọn ṣe fun Ajimọbi di ariyanjiyan nla

Nise ni awọn eeyan n gba ọrọ saare Ajimọbi ti awọn mọlẹbi rẹ ṣe bii aafin ọba bii ẹni gba igba ọti. Niṣe ni wọn ṣe saare ọkunrin naa ringindin. Aga wa nibẹ, ohun amuletutu wa nibẹ, bẹẹ ni wọn fa ina sibẹ to mọlẹ rokoso. Ẹrọ amunawa paapaa wa nibẹ bi ina ijọba ba lọ.

Bawọn kan ṣe n sọ pe ohun to daa ni, pe ko si ohun ti mọlẹbi ko le ṣe fun eeyan wọn ti wọn ba fẹran, ṣugbọn to ku.
Ṣugbọn awọn kan sọ pe ifowoṣofo gbaa ni. Wọn ni ẹni to ti ku ti ba tiẹ lọ, oku rẹyin. Ati pe wọn ko nilo iru nnkan bẹẹ.

Awọn eeyan yii sọ pe wọn le lo awọn owo ti wọn na danu lasan yii fun nnkan daadaa mi-in. Wọn le fun awọn alaini lawujọ

Ẹ gbọ, ki lẹyn ri sọ si i.

Fidio:

4 thoughts on “Saare ti wọn ṣe fun Ajimọbi di ariyanjiyan nla

  1. Ko so ohun to buru ni be won ko fe gbagbe eni won opolopo awon olowo lo monse irue baba awolowo nko abiola nko ati awon minran tao le daruko ati awon minran ta o mon awa omo yoruba agbadun ka yo oju si ohunti kokanwa bi won tun se sarere bi o se de Dara etun ma roroso kinlode

Leave a Reply