Tag Archives: herdmen

Awọn Fulani ya wọ ipinlẹ Ọyọ tibọntibọn, agbegbe Ìbàràpá lawọn agbofinro ti da wọn duro

Ọlawale Ajao, Ibadan Lẹyin ọjọ mẹta ti awọn agbofinro ilẹ Yoruba, Amọtẹkun ẹka ipinlẹ Ọyọ, ti lọọ gbéjà ka awọn afurasi ajinigbe mọ ibuba wọn ninu aginjù igbo, ti wọn sì yinbọn pa mẹta ninu awọn agbesunmọmi náà lẹyìn ija alagbara to waye laarin wọn, awọn Fulani ti  dihamọra ija …

Read More »
//eephaush.com/4/4998019