Tinubu ṣabẹwo si Yẹmi Ọṣinbajo

Adewumi Adegoke
Ẹni ti wọn ṣẹṣẹ yan gẹgẹ bii oludije fun ẹgbẹ oṣelu APC funpo aarẹ, Aṣiwaju Tinubu, ti ṣabẹwo si Igbakeji Aarẹ, Ọjọgbọn Yẹmi Ọṣinbajo, ni ile ijọba, niluu Abuja, lalẹ Ọjọbọ, Tọsidee, ọsẹ yii.
Lẹyin abẹwo to ṣe sọdọ Aarẹ Buhari lo ṣe abẹwo iyanu yii si ile Ọṣinbajo, ti wọn jọ ki ara wọn, ti Ọṣinbajo si ki i ku oriire iyansipo naa. Gomina ipinlẹ Eko, Babajide Sanwoolu wa ninu awọn to kọwọọrin pẹlu rẹ lọ sile Igbakeji Aarẹ naa.

About Alaroye

Journalist, Press man and News Researcher of the federal Republic of Nigeria

Check Also

Adajọ agba ilẹ wa, Tanko Muhammad ti kọwe fipo silẹ

Adewumi Adegoke Adajọ agba ile-ẹjọ to ga ju lọ nilẹ wa, Onidaajọ Ibrahim Tanko Muhammad, …

Leave a Reply

//lephaush.net/4/4998019
%d bloggers like this: