Wasiu Ayinde bẹ ẹgbẹ FIBAN, o loun ko ni i ṣeru ẹ mọ

Ọlájídé Kazeem

Laafin Olu Itori nipade hun ti waye l’Ọjọ̣bọ, Tsidee, ọsẹ yii, nibi ti wn ti yanju wahala to wa laarin Oluaye Fuji, Alhaji Wasiu Ayinde, atawn ẹgb srsr, eyi to ti n ja ran-in-ran-in nil lati bii j melooo kan syin.

Nibi ipade ọhun ni Wasiu Ayinde ti bẹ awọn sọrọsọrọ yii, to si fi da wọn loju pe irufẹ iwa buruku ọhun ko ni i ṣẹlẹ ni sakaani oun mọ sẹnikẹni.

Wẹrẹ bayii ni wahala ọhun bẹrẹ laarin kunrim olorin fuji yii plu gbajum srsr kan to fi ilu Abokuta ebugbe, Wle orunkni tawn eeyan tun m si MC MURPHY.

Awm yin Wasiu Ayinde ni wn klu u, ti wọn si ṣe e leṣe lọjọ ti Olu Itori n ṣọjọọbi ọgọta ọdun to pe loke eepẹ.

Iṣẹl yii gan an ni wn lo mu awgb srsr paṣẹ fun gbogbo awm gb wn kaakiri Naijiria nibi gbogbo ti redio ati tlifian ba ti n iẹ, ti awọn ọmọ ẹgbẹ ọhun si n ṣeto nibẹ wi pe wn ko gbd lo orin e m, ati pe awn yoo tun ko j hun dele Alaafin y, nibi tawn yoo ti b baba naa pe ko tete r  loye, nitori kunrin naa ko y lni ti wn le maa pe ni Mayegun gge bi oye ti ba Adeymi Atanda Alaafin fi j.

Bi r hun e wa niyn ki awn eeyan nla nla wnyi, Mayor Akinplu, gbajumọ oṣere tiata nni, Dele Odule,  Ọnarebu Bidun Akinlade atawọn eeyan nla nla mi-ịn too da si i, ti wn si ti ba wn yanju  bayii

2 thoughts on “Wasiu Ayinde bẹ ẹgbẹ FIBAN, o loun ko ni i ṣeru ẹ mọ

Leave a Reply