Wizkid, olorin taka-sufee, kan Aarẹ Buhari labuku

Afaim ki dmkunrin olorin taka-sufee nni, Aydeji Ibrahim Balogun, ni tawn eeyan tun m si Wizkid ma w wahala ijba plu bo e kan Aar Muhammed Buhari labuku.

Laip yii ni arun Koronafairọọsi klu Aar oril-ede America, Donald Trump, ati iyawo , Melania, kaakiri agbaye si ni wn ti n ki i, ti wn n adura fun un wi pe aisan hun ko ni i mna mi.

Eyi naa ni Aar Muhammed Buhari e o, bo si ti gbe e sori r abẹyẹfo rẹ, twitter, to ki Donald Trump, to si tun adura fun un pe ki lrun tete mu un lara da, bẹẹ ni Wizkid naa gba ori ẹrọ abẹyẹfo rẹ, twitter l, nib gan-an lo ti kan Aar oril-ede yii labuku. O kọ ọ sibẹ pe “Baba, r Donald Trump ko kan yin rara, awlpaa atawtlmuy Sars ti wn n pa awd ni Naijiria lojoojum ni k  ba wa mojuto, ko sohun to kan yin ninu r America, oril-ede tiyin ni k  kju m.”

Bo ti e k  niyn o, ohun tawn eeyan si n s ni pe afaim ki ohun to e yii ma di ran si i lrun, nitori ohun ti Buhari e ki i e ohun to buru rara. Wn ni, kaakiri agbaye lawn eeyan ti n ki Aar Amrika, toun naa ba si ki i, eyi ko y ko fa iru abuku bẹẹ.

Bakan naa lawon mi-in s pe ko si wahala ninu ki eeyan s ero kan , ohun ti Wizkid e, ero kan  lo gbe jade. Ati pe t mniyan paapaa faaye gba a daadaa lab ofin.

 

7 thoughts on “Wizkid, olorin taka-sufee, kan Aarẹ Buhari labuku

  1. Kosi ohun to buru ninu nkan to so yen ,ki ijoba naijiria bawa wa nkan se si ipaniyan L’ori lede yi ni ooooo
    There is nothing bad about his comment,let the Nigerian government take a quick intervention to curb d unlawful killings that rampered every where today.
    GOD BLESS NIGERIA
    GOD BLESS US WE THE VOICELESS NIGERIANS
    ONE NIGERIA WE MOVE FORWARD

Leave a Reply