Wọn ṣi n wa awọn eeyan tawọn ajinigbe ji gbe lọ l’Ekiti

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti

Lalẹ ọjọ Ẹti, Furaidee, lawọn ajinigbe kan ti wọn to mẹwaa ya bo ilu Isinbọde-Ekiti, nijọba ibilẹ Ila-Oorun Ekiti, nibi ti wọn ti gbe eeyan mẹta.

ALAROYE gbọ pe ibudo kan ti wọn ti n ta pako ni wọn kọkọ ti ja awọn eeyan lole ki wọn too ko awọn meji, bẹẹ ni wọn si tun gbe adari ileeṣẹ ijọba kan lẹyin ti wọn da ibọn bo mọto rẹ, ti wọn si ṣe dẹrẹba rẹ leṣe.

About admin

Check Also

Pasitọ Chibuzor fun awọn obi Deborah ni ile fulaati mẹrinla atawọn ẹbun mi-in

Monisọla Saka O da bii pe iku Deborah, ọmọbinrin ti awọn awọn kan juko pa, …

Leave a Reply

//thaudray.com/4/4998019
%d bloggers like this: