Wọn dana sun ile ẹgbẹ APC l’Ondo

Bo tilẹ jẹ pe ofin konile-gbele wa nipinlẹ Ondo, sibẹ, awọn ọdọ kan ti kọ lu ile ẹgbẹ oṣelu APC to wa niluu Akurẹ, ti wọn si dana sun un.

Agbẹnusọ ẹgbẹ oṣelu naa, Alex Kalẹjaye, ti sọ pe ki i ṣe awọn to n ṣewọde ta ko ẹṣọ agbofinro lo kọlu olu-ile ẹgbẹ naa bi ko ṣe awọn ọmọ ẹgbẹ PDP ti inu n b

Leave a Reply