Wọn ti bura fun Joe Biden gẹgẹ bii Aarẹ Amẹrika kẹrindinlaaadọta

Ni deede aago mẹfa ku iṣẹju diẹ ni Adajọ John G. Roberts Jnr. ṣebura fun Aarẹ Amẹrika tuntun, Joe Biden.

Eyi tumọ si pe lati oni lọ, aṣẹ ati agbara gẹgẹ bii Aarẹ Amẹrika ti dọwọ rẹ.

Ọkunrin yii lo gbapo lọwọ Donald Teump, aarẹ Amẹrika to fipo naa silẹ lanaa, lẹyin ọdun mẹrin to ti lo lori aleefa.

Biden yii ni igbakeji aarẹ ilẹ naa tẹlẹ, Barak Obama.

Leave a Reply