Wọn ti dana sun awọn mọto BRT ni Oyingbo

 Faith Adebọla

Ẹ ka ileesẹ BRT to wa ni Oyingbo ni awọn to n fehonu han ta ko bi awọn ṣọja ṣe pa awọn ọdọ to n sewọde ni Lẹkki lọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọsẹ yii ti jo kanlẹ.

Niṣe ni wọn dana si gbogbo awọn mọto ijọba yii, ti gbogbo rẹ si n jona gidigidi di ba a ṣe n kọ iroyin yii.

 

Leave a Reply