Wọn ti dana sun NPA ni Apapa

Aderohunmu Kazeem

Ileeṣẹ ijọba apapọ to n ṣakoso ọkọ oju omi ilẹ wa ni wọn tun ti lọọ kọ lu bayii.

Bi a ti ṣe n ko iroyin yii jọ, lalaala ni ina n jo ileeṣẹ ọhun to wa ni Apapa, l’Ekoo. Awọn ọdọ ti inu buruku n bi ni wọn sọ pe wọn kọ lu ileeṣẹ naa.

 

Leave a Reply