Wọn ti dana sun too geeti Lekki-Ikoyi

Iroyin to tẹ ALAROYE lọwọ bayii ni pe wọn ti dana sun too geeti Ikoyi.

Ko ti i sẹni to mọ awọn to ṣiṣẹ naa, ṣugbọn awọn kan ni o ṣee ṣe ko jẹ awọn ọdọ ti inu n bi pelu bi awọn ṣọja ṣe yinbọn pa awọn kan ninu wọn lo ṣiṣẹ naa. Ṣugbọn a ko ti i le fidi eleyii mulẹ.

One thought on “Wọn ti dana sun too geeti Lekki-Ikoyi

Leave a Reply