Wọn ti kọ lu ọfiisi SARS l’Ekoo, niṣe ni wọn dana sun ẹru ti wọn ba nibẹ

Aderohunmu Kazeem

Awọn ọdọ ti wọn n fẹhonu han kiri Eko tun ti kọ lu ọfiisi awọn SARS to wa ni agbegbe Cement, lojuna Iyana-Ipaja si Osodi, l’Ekoo.

Bi wọn ti ya wọ ọfiisi ọhun ni wọn n ko awọn dukia ti wọn ba nibẹ jade, ti wn si dana sun un.

Bi wọn n sun aṣọ awọlọpaa hun lw, bẹẹ lkan ninu awd to n binu kiri yii mu ori orule fiisi naa gun, to si br si i ja a.

Leave a Reply