Wọn ti sinku Jimoh Isiaka tawọn SARS yinbọn pa l’Ogbomọṣọ

Ọgọọrọ awọn eeyan ni wọn ṣi n ba mọlẹbi ọmọkunrin kan ti wọn pe ni Jimọh Ibrahim tawọn SARS yinbọn fun lasiko ti awọn ọdọ n ṣewọde kaakiri niluu Ogbomọṣọ, nipinlẹ Ọyọ, ni ọjọ Abamẹta, Satide, ọsẹ ta a lo tan yii.

Nibi ti ọmọkunrin naa durosi ni ọn ni ibọ aọn SARS ti lọọ ba a. Oju ẹsẹ ni wọn sare gbe e lọ si ọsibitu, ṣugbọn omọkunrin naa pada jade laye.

Irọlẹ ọjọ Abamẹta naa ni wọn ti sinku ọmọkunrin naa. Igbe aro buruku ni baba ọmọ naa mu bọnu ti aọn eeyan si n parọwa fun un pe ko ṣe suuru.

Leave a Reply