Monisọla Saka
Lintex Ogale, ọrẹkunrin ti ọdọmọbinrin kan, Deborah Moses, tawọn eeyan tun mọ si Debrah Porsche, ti fẹ ri, amọ ti wọn ti fira wọn silẹ lati bii ọdun meji bayii, ti pada gbẹmi ọmọbinrin naa ninu ile ẹ to wa l’Ekoo.
Gẹgẹ bi Premium Times ṣe sọ, ninu ile tọmọbinrin yii n gbe ninu Estate kan nipinlẹ Eko, ni afurasi to ti wa latimọle ọlọpaa bayii lọọ pa a si lalẹ Ọjọbọ, Tọsidee, ọjọ kẹrin, oṣu Kẹsan-an, ọdun yii.
Meddy Olutu Imanoel, to sun











Leave a Reply