Nitori bi wọn ṣe pa Kabiyesi ti wọn tun dana sun oku ẹ, awọn eeyan sa kuro niluu

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ko sẹni to ti i mọ ẹni ti wọn jẹ o, iyẹn awọn…

Tinubu la fẹ ko bọ sipo aarẹ lẹyin Buhari – Ẹgbẹ awọn Fulani darandaran

Faith Adebọla Ẹgbẹ awọn Fulani darandaran lorileede yii, Miyetti Allah Cattle Breeders Association (MACBAN), ti kede…

Fulani darandaran tun ya wọ ilu Okelusẹ, wọn paayan meji, wọn tun ṣe awọn mi-in leṣe

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Eeyan meji lo ku, nigba tawọn mi-in tun fara gbọta ìbọn ninu akọlu…

Dẹrẹba danfo pade iku ojiji ni Sango, tirela to ko okuta lo wo lu u

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ni nnkan bii aago marun-un kọja ogun iṣẹju ni dẹrẹba awakọ danfo kan…

Iyawo ni Yaqub kọ lo ni akọbi wọn to ti n tọju fọdun mẹrinla, lo ba daku gbọnrangandan

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Yaqub Ganiyu nikan lo le ṣapejuwe iru ibanujẹ to wa lọkan ẹ latigba…

Ọṣun 2022: Kẹni to ba fẹẹ dije lọọ gba fọọmu, emi o bẹru idibo abẹle o -Oyetọla

Florence Babaṣọla, Oṣogbo ‘Anfaani wa fun ẹnikẹni to ba fẹẹ dije funpo gomina labẹ ẹgbẹ oṣelu…

Ero rẹpẹtẹ lẹyin Ọṣinbajo lasiko to ṣabẹwo si Ogbomọṣọ, Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Bii omi lero n wọ tẹle Igbakeji Aarẹ ilẹ wa, Ọjọgbọn Yẹmi Ọṣinbajo,…

Ko ni i ṣẹku agbebọn kankan mọ, ma a ṣẹgun gbogbo wọn ki n too kuro nipo-Buhari

Faith Adebọla  Olori orileede wa, Aarẹ Muhammadu Buhari ti ṣeleri pe oun maa ri i daju…

Awọn aṣaaju PDP fẹẹ gbe Ọbasanjọ mọra nitori ibo ọdun to n bọ, ni baba ba loun o ṣoṣelu mọ

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ibi gẹrẹjẹ la a ba’gba lo ku ti Oloye Oluṣẹgun Ọbasanjọ n sọ…

O ṣi ku ọdun mẹrin kipo aarẹ too le kuro nilẹ Hausa – Awọn aṣofin APC Ariwa

Faith Adebọla Agbarijọ awọn ọmọleegbimọ aṣofin lawọn ipinlẹ to wa lagbegbe Ariwa/Ila-Oorun ilẹ wa ninu ẹgbẹ…

Mi o fara mọ ki wọn tu Sunday Igboho silẹ lahaamọ-Seriki Fulani Igangan

Faith Adebọla Ṣe ẹ ranti Abdulkadir Saliu, Seriki Fulani ilu Igangan, lagbegbe Ibarapa, Oke-Ogun, nipinlẹ Ọyọ,…