O ma ṣe o! Ogunjinmi ajagajigi oogun ti ku o

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọkan pataki lara awọn agba oṣere tiata ilẹ wa nni, Ọgbẹni Ganiyu Oyeyẹmi…

Ina ẹlẹntiriiki to ja gbẹmi iya, awọn ọmọ ẹ wa lẹsẹ-kan-aye ẹsẹ-kan-ọrun

Monisọla Saka Ina ẹlẹntiriiki to ṣẹ yọ nibi ẹrọ amunawa tiransifọma to wa ninu ọja kan…

 Nibi to ti n sare asapajude, ọmọ Yahoo f’ọkọ paayan mẹta l’Akungba Akoko

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Diẹ lo ku ki rogbodiyan bẹ silẹ niluu Akungba Akoko, nipinlẹ Ondo, lẹyin…

Ọwọ ọlọpaa tẹ akẹkọọ poli pẹlu fọọmu igbani-wọle sinu ẹgbẹ okunkun n’llọrin

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Kwara ti fọwo ofin mu akẹkọọ ileewe gbogbonise ijọba apapọ…

Agboọla Ajayi ti ẹgbẹ PDP ni yoo koju Ayedatiwa ninu ibo gomina Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Igbekeji Gomina ipinlẹ Ondo ni saa kin-in-ni Oloogbe Rotimi Akeredolu, Ọnarebu Agboọla Ajayi,…

Ileeṣẹ ọlọpaa ti sọ agbofinro to yinbọn paayan ni LAUTECH satimọle

Ọlawale Ajao, Ibadan Gbogbo awọn ọlọpaa ti wọn kopa ninu iṣẹlẹ buruku to waye niluu Ogbomọṣọ,…

Kayeefi! Inu ọkọ ti baale ike kan n wọ lọ si Eko lati ilu Ilọrin lo dakẹ si

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Baale ile kan to to ẹni ọgọta ọdun, lo pade iku ojiji lasiko…

Ebi buruku lọkọ mi fi n pa emi atawọn ọmọ, mi o fẹ ẹ mọ-Raheemat

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ṣe owe Yoruba kan lo sọ pe ebi ki i wọnu kọrọ mi-in…

Ẹfun abeedi, ọmọ Naijiria yii luyawo ẹ pa niluu oyinbo, eyi lohun to lo ṣe

Monisọla Saka Ibinu odi ti mu ki ọkunrin ọmọ orilẹ-ede Naijiria toun pẹlu awọn ẹbi ẹ…

Ṣẹyin naa ti gbọ ohun ti ọba ilu Fiditi ti wọn rọ loye ṣe?

Ọlawale Ajao, Ibadan Lẹyin ti wọn ti rọ Onifiditi tilu Fiditi loye, ija ṣẹṣẹ bẹrẹ lori…

Wọn fẹsun ayederu iwe-ẹri kan Ọmọọba Adebomi to fẹẹ dupo ọba Ararọmi Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ileeṣẹ ọlọpaa lati ẹkun kẹtadinlogun (Zone 17), Akurẹ, ti kede pe ọwọ awọn…