Mo ri ohun to ṣẹlẹ nigba ti Yẹmi kede fun gbogbo aye pe oun fẹẹ du ipo aarẹ. Ere buruku ni Bọla (Tinubu) sa nibi yoowu to wa, nigba ti oloju si fi maa ṣẹju, Bọla ti wa l’Abuja, wọn lo n ṣepade pẹlu awọn gomina APC, loootọ lo si …
Read More »Ki Bisi mura si i, ki Bọla naa mura si i
ỌMỌỌDỌAGBA Ohun to ṣẹlẹ lọsẹ to kọja yii ki i ṣe tuntun. Ohun ti mo sọ fun gbogbo awọn ti wọn n fi foonu daamu mi, ati awọn ti wọn n wa mi wa lati igba ti wọn ti gbọ ohun to ṣẹlẹ, ati bawọn oniweeroyin ti n gbe kinni …
Read More »Ọrọ to yẹ ki Tunde ba ọrẹ rẹ tuntun sọ
Nigba ti mo kọ ọrọ lori Tunde (Pasito Bakare), jade lọsẹ to kọja, oriṣiiriṣii iwe ni mo n gba lori aago, diẹ ninu awọn atẹjiṣẹ naa si ba mi lẹru. Ohun to jẹ ko ba mi lẹru ni pe awọn eeyan wa ki i fi ara balẹ gbọ ọrọ, nigba …
Read More »Tunde, awọn wo ni Agba Ṣakabula?
N ko fẹẹ sọrọ si ọrọ yii rara, ṣugbọn ọrọ naa jo mi lara, nitori ki i ṣe ibi ti mo to Tunde (Pasitọ Tunde Bakare) si ni mo ba a. Ọrọ ti mo gbọ lẹnu aburo wa to n ṣiṣẹ oniwaasu yii ba mi lọkan jẹ kọja bi kinni …
Read More »Lẹta pataki si awon ọdo ọmo Yoruba (3)
Awọn ọmọ mi kan n yọ mi lẹnu, bẹẹ naa ni awọn ọrẹ mi kan ti a jọ jẹ ẹgbẹ, ati awọn mi-in ti wọn jẹ ẹgbọn fun wa. Gbogbo wọn ni wọn n daamu mi lori ọrọ to n lọ nilẹ Yoruba bayii. Ọrọ naa ni pe ‘Dandan Ni …
Read More »Lẹta pataki si awọn ọdọ ọmọ Yoruba (2)
Nigba ti a fẹẹ dibo ni ọdun to kọja, mo bẹrẹ si i pariwo ki wọn ma dibo fun Buhari. Ṣugbọn n ko deede sọ pe ki wọn ma dibo fun un o, mo ṣalaye kan fun gbogbo ọmọ Yoruba to ba n feti si mi. Alaye ti mọ ṣe nigba …
Read More »Lẹta pataki si awọn ọdọ ọmọ Yoruba patapata
Nibi ti ọrọ de duro bayii fun gbogbo ọmọ Yoruba, afi ka wa nnkan mi-in ṣe. Ohun ti mo n sọ ni pe afi ka wa ọgbọn mi-in da, bi a ba fẹẹ bọ ninu oko ẹru ti awọn oloṣẹlu ti wọn wa laarin wa ko wa si. Bi ẹ …
Read More »Nibo ni agbara Yoruba wa: Njẹ Yoruba tiẹ lagbara kankan mọ
Nigba ti ibo ọdun to kọja yii n bọ lọna, emi ati ọrẹ mi kan ja, ija naa ko pari titi di ẹnu ọjọ mẹta yii. Ọrọ kekere kan lo si fa ija naa lasiko ti ibo ọhun ku si dẹdẹ. Nibi ti wọn ti n sọrọ ẹni ti wọn …
Read More »Ẹru kan wa to n ba mi o
Mo fẹ ki a jọ yẹ awọn kinni wọnyi wo, ko ma da bii pe emi nikan ni mo n pe ara mi ni ọlọgbọn aye, tabi ko ma jẹ ironu aṣiwere lo wa lori mi ti mo n pe ni ironu gidi. Orilẹ-ede wa Naijiria yii ni ileeṣẹ ti …
Read More »Loootọ lọootọ ni mo wi fun yin, ijọba yii o daa!
Ohun ti awọn eeyan kan n sọ, ti wọn si n beere lọwọ mi bayii, ni pe ki la ti ṣe fẹẹ yanju ọrọ to wa nilẹ yii. Ki lọna abayọ? Awọn kan n beere ọrọ yii lọna to daa, wọn n beere nitori loootọ ni wọn fẹ ka rọna …
Read More »Iyatọ diẹ lo wa ninu Trump Amẹrika ati Buhari Naijiria
O da mi loju pe ọpọ awọn ọmọ wa, ati awọn ti wọn jẹ agba paapaa ni wọn ti maa ri ibo ti wọn di kọja ni orilẹ-ede Amẹrika yii bii ohun ti ko kan wọn, ti wọn aa si ti sọ pe ki lo kan awọn nibẹ, ewo ni …
Read More »