IYA BIỌLA Igbeyawo Akin ti a ṣe laipẹ yii, a kuku tun ti fi da nnkan mi-in silẹ. Baba yin ti yari mọ mi lọwọ o, o ni afi ki oun jẹ Baba Adinni ti awọn mọṣalaaṣi Oṣodi kan fẹẹ fi oun jẹ, oun ko duro mọ. Igbeyawo ti a …
Read More »Igbeyawo Akin: Ṣe aye mi daa tabi ko daa
A ti lọọ tọrọ iyawo Akin. N ko le sọ pe o dun mi tabi ko dun mi, nitori inawo naa ko lọ bi mo ṣe fẹ. Niṣe ni pasitọ to jẹ baba iyawo wa n ṣe bii ẹni pe nnkan eewo ni ọmọ oun ṣe, to ṣaa n ṣe …
Read More »Ẹjọ ni pasitọ yii fẹẹ ro, ọrọ lo si maa fi gbọ
Ẹ wo o, o daa ki eeyan naa daa. Bi eeyan ba daa, toun naa jẹ ọmọluabi, yoo ṣoro ki wahala kan too ba a. Nigba ti ọrọ yii ṣẹlẹ, mo fẹẹ le sọ pe lọjọ ti mo ti wa l’Oṣodi yẹn, tabi ti mo ti n ṣe ka-ta-ka-ra mi …
Read More »Wọn ma fọlọpaa mu ọmọ mi o
Emi o le fi taratara da si ọrọ awọn Sẹki yẹn, ọrọ lọkọ-laya ni, nigba tẹni to si ni oun fẹẹ waa fẹjọ ọmọ mi sun ko ti wi kinni kan, mo mọ pe ko ti i ka a lara niyẹn, bo ba ka a lara, yoo sọrọ soke. N …
Read More »Alaaji ti waa fọgbọn tuuba, a ti tun dọrẹ pada
Alaaji, agbaaya, o kuku mọ bi oun ti ṣe n mu mi. Oun naa mọ pe mi o ki i ṣe ọmọ buruku. Ti mo ba sọ ohun to ṣe fun yin, yoo ya ẹyin naa lẹnu. Nigba ti Safu ti ba mi sọrọ, ti ọkan emi naa si ti …
Read More »Oyinbo muti, ọti n pa kuku
Ọlọrun ma jẹ ki wọn mu baba yin lọ. Emi kuku ti kilọ fun un, Ọlọrun ma jẹ ki wọn gbe e lọ. Awọn ti wọn ṣofin korona ni o, nitori gbogbo wa ni wọn kilọ fun pe kinni naa ti tun n ṣe awọn eeyan, pe ki gbogbo eeyan …
Read More »Ẹ ba mi dupẹ, Sẹkinatu Abẹjẹ, ọmọ mi ti bimọ o
Ẹ wo o, nnkan ti waa bajẹ patapata. Ọrọ aye yii, ti mo ba ni ki n maa ro o, oluwa ẹ ko ni i ṣe nnkan meji mọ o. Ṣe ẹ mọ pe nigba kan, ilu oyinbo ni opin irin-ajo fun awọn ọmọ wa. Ti wọn ba ti lọ sọhun-un, …
Read More »Ibinu Alaaji bii ibinu Abija, Ọlọrun ma jẹ n ri i
Ka ṣa maa ṣe rere. Ṣe ẹ mọ pe gbogbo igba ni mo maa n wi bẹẹ. Ka ṣa maa ṣe rere o. Ani n ko mọ ohun ti mo fẹẹ fun awọn ọmọ ti mo ba ni ṣọọbu wa yẹn. Mo mọ pe ni gbogbo igba ti wahala wa …
Read More »Ani, aa ranti tilẹkun ṣọọbu lọjọ ofin konilegbele
Ọrọ Aunti Sikira ati ọkọ ẹ ni mo n yanju nigba ti wahala to ṣẹlẹ lọṣẹ to kọja yii ṣẹlẹ. Gbogbo eto ti mo ṣe lo ṣiṣẹ. Iya Walia ti ba mi rin gbogbo irin to ku ti mo fẹ ko rin, Safu naa ti jiṣẹ ti mo ran an. …
Read More »Aunti Sikira jẹwọ fun mi, o ni loootọ lọkunrin yẹn boun ṣe aṣemaṣe
Eke niyaale mi, Iya Dele. Eke gidi ni. Abi bawo lo ṣe mọ pe panti ti wọn mu wa sile wa, panti Aunti Sikira ni. Inu ile ni kaluku n sa panti ẹ si nigba taye ti daye ka maa ji ara ẹni ni pata kiri yii, ko sẹni to …
Read More »Bẹẹ ki i ṣe eleyii ni yoo gbe Anti Sikira kuro nile Alaaji
Niṣe ni mo n bẹ Safu ko ma sọ ọrọ ilẹ ẹ ti a lọọ ra fẹni kan, mo ni ko fun mi laaye ki n sọ fun wọn nikọọkan. Ẹni kan ṣoṣo ti n ko le gbe iru nnkan bẹẹ yẹn gba ẹyin ẹ kọja naa ni Sẹki, ohun …
Read More »