Ileeṣẹ ọlọpaa doola ẹmi arinrin-ajo mẹrin ninu mẹfa tawọn ajinigbe ji gbe ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Kwara ti kede pe awọn ti doola ẹmi arinrin-ajo mẹrin…

2023: Mo fi ori-ade bẹ ẹyin agbaagba Yoruba lati ma ṣe jẹ ki anfaani nla yii fo wa ru-Oluwoo

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Oluwoo ti ilu Iwo, Ọba Abdul Rosheed Adewale Akanbi, ti parọwa si gbogbo…

Ṣaja ti Titilayọ gbagbe sibi to ti lọọ ṣaaji foonu lo lọọ mu ti Musa fi fipa ba a lo pọ n’Ibadan

Faith Adebọla Ile-ẹjọ Majisreeti kan to fikalẹ siluu Ibadan, nipinlẹ Ọyọ, ti paṣẹ lọjọ Aje, Mọnde,…

Ijọba Eko tun fofin de ọkada lawọn ijọba ibilẹ mẹrin mi-in

Monisọla Saka, Eko Gomina ipinlẹ Eko, Babajide Sanwo-Olu, ti tun paṣẹ pe ki iṣẹ ọkada ṣiṣe…

Lẹyin ti wọn gba miliọnu meji Naira, awọn ajinigbe tu Sulia silẹ n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Sulia, ọmọ gbajumọ olori nni, Alaaja Kẹhinde Ejide, ti awọn ajinigbe ji gbe…

Amọtẹkun mu awọn Fulani mọkanlelogun ti wọn sa pamọ sinu tirela l’Ọṣun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọwọ ẹṣọ Amọtẹkun ipinlẹ Ọṣun ti tẹ awọn Hausa/Fulani ti wọn to mọkanlelogun…

Nibi ti wọn ti n y’ayọ pe wọn kẹkọọ-jade, akẹkọọ mẹrin ku sinu omi okun l’Ekoo

Inu ipayinkeke lawọn eeyan agbegbe Lekki, nipinlẹ Eko, wa bayii lẹyin tawọn ọmọ mẹrin kan ri…

Ẹgbẹ oṣelu PDP Ọṣun lawọn ko ni i kopa ninu idibo ijọba ibilẹ ti OSIEC fẹẹ ṣe

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ẹgbẹ oṣelu PDP nipinlẹ Ọṣun ti sọ pe awọn ko ni i kopa…

Ọlọpaa yinbọn pa ọlọkada l’Abule-Egba

Monisọla Saka Rogbodiyan bẹ silẹ nirọlẹ ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, nitori bi wọn ṣe ni awọn agbofinro…

Awọn ọmọ ẹgbẹ APC kan ṣewọde ta ko ki Musulumi jẹ aarẹ ati igbakeji

Monisọla Saka Ọgọọrọ awọn eekan ati alatilẹyin ẹgbẹ oṣelu APC ni wọn fọn sori titi nipinlẹ…

Ọga ọlọpaa patapata paṣẹ eto aabo to rinlẹ kaakiri awọn ileewe 

Monisọla Saka, Eko Lọjọ Aiku, Sannde, ọsẹ yii, ni Ọga ọlọpaa patapata lorilẹ-ede yii, Usman Baba,…