Awọn eleyii n gbowo ipa lọwọ awọn onimọto, wọn loṣiṣẹ ijọba Eko lawọn

Faith Adebọla, Eko Ọrẹ timọtimọ ni awọn ọkunrin mẹrin yii, Taiwo Falọdun, ẹni ọdun mejidinlaaadọta, Adedire Ọlaniyi, ẹni ọdun mejilelogoji, Fẹmi Ọṣunkọya, ẹni ọdun mẹtalelaaadọta ati Ọlawale Edu, ẹni ọdun mọkanlelaaadọta, ṣugbọn rikiṣi lo pa wọn pọ ti wọn fi dọrẹ, iṣẹẹbi ti wọn fẹsun ẹ kan wọn ni pe …

Read More »

Wọn ti tu Oriyọmi Hamzat silẹ lahaamọ

Iroyin to tẹ ALAROYE lọwọ ni pe awọn ọlọpaa ti tu Oludasilẹ Redio Agidigbo, Oriyọmi Hamzat ti wọn gbe lọ si akata wọn silẹ. Ninu atejade kan to tẹ ALAROYE lọwọ, eyi ti Adebayọ Yousuph Grey, fọwọ si lorukọ awọn alaṣẹ ileeṣẹ naa ni wọn ti sọ pe ‘‘Wọn ti …

Read More »

Buhari ati iyawo ẹ lọ si Equitorial Guinea

Faith Adebọla Lai ka bi oriṣiiriṣii apero abẹnu ati eto idibo lati yan awọn ti yoo dije fun oniruuruu ipo lasiko idibo gbogbogboo ọdun 2023 lorukọ ẹgbẹ oṣelu rẹ, All Progressives Congress, (APC), eyi to n lọ lọwọ si, ati bi eto idibo lati yan oludije funpo aarẹ laarin awọn …

Read More »
//unbeedrillom.com/4/4998019