Ọwọ wa ti tẹ awọn afurasi kan lori akọlu to waye ni ṣọọsi Ọwọ-Adelẹyẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Awọn afurasi kan to ṣee ṣe ki wọn mọ nipa iṣẹlẹ akọlu to waye ninu sọọsi Katoliiki Francis Mimọ tilu Ọwọ lọjọ Aiku, Sannde, ọjọ karun-un, oṣu Kẹfa yii, lọwọ ti tẹ, ti wọn si ti wa nikaawọ ẹṣọ Amọtẹkun ipinlẹ Ondo lọwọlọwọ. Alakooso ẹṣọ Amọtẹkun nipinlẹ …

Read More »

Nitori to n jade pẹlu ọrẹkunrin mi-in, Fatai atawọn ọrẹ ẹ lu ọrẹbinrin rẹ lalubami ni Kwara

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Akolo ileeṣẹ ọlọpaa ni ọdọmọkunrin kan, Fatai, wa bayii. Niṣe lo gbimọ-pọ pẹlu awọn ọrẹ ẹ, wọn bọ ọrẹbinrin rẹ, Adukẹ, sihooho, wọn si lu u bii bẹmbẹ nitori ẹsun pe o n fẹ ọkunrin miiran. Alukoro ileeṣẹ ọlọpaa nipinlẹ Kwara, SP Ajayi Okasanmi, sọ pe ọwọ …

Read More »

Lẹyin tawọn meje ti lọ, sẹnetọ mejidinlogun tun fẹẹ binu kuro lẹgbẹ oṣelu APC

Faith Adebọla Ko din ni wakati meji gbako ti Alaga apapọ ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress (APC), Sẹnetọ Abdullahi Adamu fi tilẹkun mọri ṣepade aṣelaagun pẹlu awọn sẹnetọ ti wọn jẹ ọmọ ẹgbẹ oṣelu naa nileegbimọ aṣofin agba, l’Abuja, l’Ọjọruu, Wẹsidee, ọjọ kejidinlogun, oṣu Kẹfa yii. Eyi ko ṣẹyin bi …

Read More »

Oyebanji, igbakeji rẹ gba iwe-ẹri mo yege Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Gomina ti wọn ṣẹṣẹ dibo yan nipinlẹ Ekiti, Ọgbẹni Biọdun Oyebanji ati Igbakeji rẹ, Arabinrin Monisade Afuyẹ, ti gba iwe-ẹri mo yege lati ọwọ ajọ eleto idibo, eyi to n tọka si aṣeyege wọn ninu eto idibo gomina to waye …

Read More »
//thaudray.com/4/4998019