Oludasile Ìwé Iroyin Alaroye, Ogbeni Àlàó Adedayo, yóò bá gbogbo agbaye sọ̀rọ̀ nípa èdè Yoruba lọ́jọ́ Sannde yìí [Alaye…]

Oludasile Ìwé Iroyin Alaroye, Ogbeni Àlàó Adedayo, yóò bá gbogbo agbaye sọ̀rọ̀ nípa èdè, àṣà àti…

Gbogbo ẹyin tẹ ẹ ti gba abẹrẹ Koro, ẹ si tẹsiwaju lati maa lo ibomu yin o – ijọba Kwara

  Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọ Ẹti, Furaidee, opin oṣe to kọja yii ni ijọba ipinlẹ Kwara,…

Ile-ẹjọ yọ awọn alaga kansu mẹrẹrindinlogun nipo ni Kwara

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọ Ẹti, Furaidee, ọṣẹ to kọja yii, ni ile-ẹjọ giga kan to jokoo…

Ọkada ni Umar ji gbe tọwọ fi tẹ ẹ n’llọrin

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin   Ajọ ẹṣọ alaabo ṣifu difẹnsi, ẹka ti ipinlẹ Kwara, ti mu ọkunrin…

FIDIO: BI WỌN BA FẸẸ GBE MI WA SI NAIJIRIA KI WỌN MAA GBE MI BỌ, MO FARA MỌ GBOGBO OHUN TO BA ṢẸLẸ-IGBOHO

FIDIO:OMỌ ALE YORUBA NI YOO SỌ PE OUN KO FARA MỌ KA DA DURO

Fidio: ÈRÒ RẸPẸTẸ NÍBI ỌDÚN SÀNGÓ LÁÀFIN Ọ̀YỌ́

fidio: AKỌSILẸ ỌLỌRUN YOO ṢẸ LORI SUNDAY IGBOHO

ỌMỌ NAIJIRIA Ẹ GBA MI O, MI O KI I ṢE IYA AJẸ O, WỌN FẸẸ FI BA MI LORUKỌ JẸ NI

FIDIO: Ẹ GBÀ MÍ LỌ́WỌ́ ÌJỌBA ÈKÓ, MI Ò NÍ ÀRÙN KÒRÓNÀ, WỌN Ò SÌ JẸ́ KÍ N LỌ

Awọn Iyalọja naa ko mu ọrọ ‘Yoruba Nation’ ni kekere mọ o