Awọn Iyalọja naa ko mu ọrọ ‘Yoruba Nation’ ni kekere mọ o

Lẹyin ti adajọ sun igbẹjọ si ọjọ Ẹti, Furaidee, wọn ti da Sunday Igboho pada satimọle

Jọke Amọri Ọjọ Ẹti, Furaidee, ọjọ kẹtalelogun, oṣu yii ni ireti wa pe wọn yoo da…

Ọjọ Ẹti, ni wọn fi idajọ Sunday Igboho si

Ọjọ Ẹti, Furaidee, ọla ni ile-ẹjọ giga to jokoo gbọ ẹjọ naa ni orileede Olominira Benin…

Awọn ọmọ Yoruba rẹpẹtẹ ya bo kootu Benin, nibi ti wọn ti fẹẹ gbọ ẹjọ Sunday Igboho

Faith Adebọla Ni deede aago mẹrin kọja iṣẹju marun-un ni wọn ṣilẹkun ile-ẹjọ fun awọn alatilẹyin…

Wọn ti gbe Sunday Igboho de kootu, awọn ọba Yoruba ni Benin ṣatilẹyin fun un

Jọke Amọri Ni ba a ṣe n sọrọ yii, ajijagbara ọmọ Yoruba nni, Sunday Adeyẹmọ ti…

Ọga agbẹjọro kan lati orileede France ni yoo ṣiwaju awọn lọọya ti yoo duro fun Sunday Igboho ni kootu Benin

Jọke Amọri  Iroyin to n tẹ ALAROYE lọwọ bayii lori ọrọ ajijagbara ọmọ Yoruba nni, Oloye…

Eeyan mẹrin ku ninu mọlẹbi kan, meji dero ileewosan, eefin jẹnẹretọ lo pa wọn ni Kwara

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin O kere tan, eeyan mẹrin ti ku ninu mọlẹbi kan, ti meji si…

Iṣoro Naijiria kọja eyi ti Buhari le yanju, ki ẹnikẹni ma ro pe ayipada yoo wa ṣaaju 2023 – Biṣọọbu Adeoye

Alukooro igbimọ awọn Biṣọọbu lagbaaye (World Bishops Council) nilẹ Afrika, Biṣọọbu Ṣeun Adeoye, ti sọ pe iṣoro…

fidio: ÀWỌN ỌMỌ YORÙBÁ FI ÀÌDUNNÚ WỌN HÀN SÍ SUNDAY ÌGBÒHO TÍ WỌ́N MÚ

Fidio: AWỌN DSS TI MU SUNDAY IGBOHO NI KUTỌNU

Awọn DSS ti mu Sunday Igboho

Iroyin to n tẹ wa lọwọ ni pe ileeṣẹ DSS, iyẹn awọn ọtẹlẹmuyẹ, ti mu Oloye…