Iru ki waa leleyii, Mustapha pa lanledi rẹ nibi to ti fẹẹ fipa ba a lo pọ l’Akurẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọkunrin ara Togo kan, Gbègèlè Mustapha, ti wa nikaawọ awọn ọlọpaa ipinlẹ Ondo,…

Nitori ibalopọ ati jibiti, wọn le olukọ ati oṣiṣẹ fasiti mẹtala danu

Faith Adebọla Awọn alakooso Fasiti Ambrose Ali (AAU), to wa nipinlẹ Edo, ti kede pe lẹyin…

Ọsẹ yii nile-ẹjọ to ga ju lọ maa dajọ lori iyansipo Tinubu ati Shettima

Faith Adebọla  Pẹlu bo ṣe ku ọsẹ kan pere ti wọn yoo ṣebura wọle fun aarẹ…

Ọwọ tẹ awọn meji ti wọn sa lọgba ẹwọn Kuje 

Adewale Adeoye Awọn alaṣẹ ọgba ẹwọn kan ti wọn n pe ni ‘Kuje Correctional Centre’ to…

Gomina Kaduna rọ ọba meji loye

Adewale Adeoye Nigba to ku ọjọ diẹ ko kuro nipo gẹgẹ bii gomina ipinlẹ Kaduna, Malam…

Ẹ ma mikan, ẹni to kunju oṣuwọn ni mo fẹẹ gbejọba silẹ fun-Buhari

Adewale Adeoye Bo ṣe ku diẹ ki iṣakoso ijọba Muhammadu Buhari pari, Aarẹ orileede yii ti…

Loootọ ni wọn ba foonu iya to ku lọwọ mi, ṣugbọn emi kọ ni mo pa a-Sunday

Oluṣẹyẹ Iyiade, Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ondo ti ṣafihan  Mima Chinecherem, ìyẹn ọmọkunrin ọmọọdun mẹtadinlọgbọn kan tọwọ…

Wọn ti wọ baba onile to lodi sofin eto ikọle lọ siwaju adajọ

Ismail Adeẹyọ Baba onile kan, Kenneth Okenini, ni wọn ti wọ lọ sile-ẹjọ Majisreeti Ikẹja, niluu…

Awọn agbebọn ṣoro ni Kwara, wọn paayan, wọn ji owo ati foonu gbe lọ 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Afaimọ lọrọ eto aabo to dẹnu kọlẹ ni Kwara, ko ti doriṣa akunlẹbọ…

Lẹyin ti Salaudeen pari ija fun tọkọ-tiyawo tan to n lọ sile lo ku sinu koto to ja si

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọ Ẹti, Furaide, ọjọ kọkandinlogun, oṣu Karun-un yii, ni iṣẹlẹ kayeefi kan ṣẹlẹ…

Titi ti ma a fi pari ijọba mi ni wiwo ile ti ko tọna ati dida awọn oṣiṣẹ duro yoo fi waye-El-Rufai

Faith Adebọla Gomina ipinlẹ Kaduna, Mallam Nasir El-Rufai, ti sọ pe keku ile gbọ ko sọ…