Gomina Kaduna rọ ọba meji loye

Adewale Adeoye Nigba to ku ọjọ diẹ ko kuro nipo gẹgẹ bii gomina ipinlẹ Kaduna, Malam…

Ẹ ma mikan, ẹni to kunju oṣuwọn ni mo fẹẹ gbejọba silẹ fun-Buhari

Adewale Adeoye Bo ṣe ku diẹ ki iṣakoso ijọba Muhammadu Buhari pari, Aarẹ orileede yii ti…

Loootọ ni wọn ba foonu iya to ku lọwọ mi, ṣugbọn emi kọ ni mo pa a-Sunday

Oluṣẹyẹ Iyiade, Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ondo ti ṣafihan  Mima Chinecherem, ìyẹn ọmọkunrin ọmọọdun mẹtadinlọgbọn kan tọwọ…

Wọn ti wọ baba onile to lodi sofin eto ikọle lọ siwaju adajọ

Ismail Adeẹyọ Baba onile kan, Kenneth Okenini, ni wọn ti wọ lọ sile-ẹjọ Majisreeti Ikẹja, niluu…

Awọn agbebọn ṣoro ni Kwara, wọn paayan, wọn ji owo ati foonu gbe lọ 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Afaimọ lọrọ eto aabo to dẹnu kọlẹ ni Kwara, ko ti doriṣa akunlẹbọ…

Lẹyin ti Salaudeen pari ija fun tọkọ-tiyawo tan to n lọ sile lo ku sinu koto to ja si

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọ Ẹti, Furaide, ọjọ kọkandinlogun, oṣu Karun-un yii, ni iṣẹlẹ kayeefi kan ṣẹlẹ…

Titi ti ma a fi pari ijọba mi ni wiwo ile ti ko tọna ati dida awọn oṣiṣẹ duro yoo fi waye-El-Rufai

Faith Adebọla Gomina ipinlẹ Kaduna, Mallam Nasir El-Rufai, ti sọ pe keku ile gbọ ko sọ…

Ikunlẹ abiyamọ o! Akẹkọọ ogun jona ku nigba tileewe wọn gbina

Faith Adebọla Iran buruku niran ọhun, ko ṣee duro wo rara, nigba tawọn agbofinro atawọn ẹṣọ…

Ẹ wo ohun ti Bimbọ Ademoye ṣe lẹyin to gbami-ẹyẹ adẹrin-in-poṣonu to daa ju lọ

Monisọla Saka Oṣerebinrin ilẹ wa tawọn eeyan fẹran daadaa nni, Bimbọ Ademoye, to kopa ‘Arọlakẹ’ ninu…

Wọn ba oku ọlọkada ninu ile akọku lẹyin ọjọ kẹjọ ti wọn ti n wa a

 Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ileeṣẹ ọlopaa ipinlẹ Ọṣun ti bẹrẹ iwadii lori iku to pa ọmọkunrin ọlọkada…

Kootu da ẹjọ ti Atiku, Obi pe lori ki wọn ṣafihan igbẹjọ idibo aarẹ ni gbangba nu

Adewale Adeoye Ile-ejọ to n gbọ ẹsun magomago to su yọ ninu eto idibo aarẹ to…