Ọwọngogo epo: Ẹgbẹ oṣelu Labour lo wa nidii iwọde ti awọn oṣiṣẹ fẹẹ ṣe-Ọnanuga

Monisọla Saka Bayọ Ọnanuga, ti i ṣe adari eto iroyin fun awọn ikọ ipolongo ibo aarẹ…

Afurasi ọlọpaa to pa Bọlanle Raheem ni ki i ṣe inu ibọn oun lọta  naa ti jade

Monisọla Saka L’Ọjọruu, Wẹsidee, ọjọ kọkanlelọgbọn, oṣu Karun-un, ọdun yii, ni Onidaajọ Ibironkẹ Harrison, ti ile-ẹjọ…

Ma a ba Tinubu ṣiṣẹ pọ to ba ranṣẹ si mi – Bọde George

Monisọla Saka Oloye Bọde George, ti i ṣe igbakeji alaga ẹgbẹ oṣelu PDP, ẹka ti apa…

Awọn agbebọn ji aṣaaju awọn obinrin ẹgbẹ oṣelu APC meji lọ

Monisọla Saka Awọn aṣaaju obinrin ninu ẹgbẹ oṣelu APC nipinlẹ Kaduna, Hajiya Lami Awarware, ati Hajiya…

‘Awa gomina APC fara mọ bi Aarẹ Tinubu ṣe yọ owo iranwọ epo bẹntiroolu’

Adewale Adeoye Fun igba akọkọ lati igba ti Aarẹ Bọla Ahmed Tinubu ti kede pe ijọba…

Tinubu yan Femi Gbajabiamila sipo olori awọn oṣiṣẹ

Adewale Adeoye Olori orileede yii, Aarẹ Bọla Ahmed Tinubu, ti yan Olori  ileegbimọ aṣoju-ṣofin ilẹ wa,…

Ibo aarẹ: Ile-ẹjọ gba awọn iwe esi idibo ti Peter Obi ko lọ si kootu gẹgẹ bii ẹri

Monisọla Saka Ọgbẹni Peter Obi, ti i ṣe oludije funpo aarẹ labẹ asia ẹgbẹ oṣelu Labour…

Ibo aarẹ: Tinubu ati INEC rọ ile-ẹjọ lati fagi le awọn ẹri ti Atiku ko wa si kootu

Monisọla Saka Ninu igbẹjọ ẹsun idibo aarẹ to waye niluu Abuja, l’Ọjọruu, Wẹsidee, ọjọ kọkanlelọgbọn, oṣu…

Tinubu ṣepade pẹlu awọn olori eto aabo gbogbo nilẹ wa

Ọrẹoluwa Adedeji L’Ọjọbọ, Tọsidee, ọsẹ yii ni Aarẹ Bọla Tinubu ṣepade pọ pẹlu awọn olori eto…

Lẹyin ọdun mẹẹẹdọgbọn, gbajumọ oṣere tiata yii naa kọ ọkọ ẹ silẹ

Adewale Adeoye Gbajumọ oṣere tiata nni, Shaffy Bello, ti sọ idi pataki to ṣe jawee ikọsilẹ…

Nitori ọwọngogo epo bẹntiroolu, Tiwa Savage loun n pada sorileede Brazil

Adewale Adeoye Gbajumọ olorin taka-sufee nni, Tiwa Savage, ti sọ pe pẹlu bọrọ ọwọngogo epo bẹntiroolu…